Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ
Àdúntúndún àti Olàjú fara hàn lẹ́yìn ìgbà kan láti jù lori àjẹkù-òkìtì nípase Olórun ní irú ònà àjèjì àìbìkítà. Ohun to jọni lójú gan ní pe àkọsílẹ̀ ti àwon ìgbà ni pé ìgbà kòòkan dòpin si boya àjálù. Àwon eni mímọ́ mó pé Olórun joba, àtipe àwọsánmà je àmó eruku esè Bàbá Rè àti kò nìdí láti bẹ̀rù. Ó ni ìdánilójú pè àwon ìṣẹ̀lẹ̀ aburú ko ṣẹlẹ̀ lasan, àtipe àlàáfíà to ga ju àti èèyàn to mọ́ ju ni láti jẹ́ èsì towa títí láé. Ìtàn ñ se imuṣẹ àsọtẹ́lẹ̀ nìgbà gbogbo.
Ipa ònà àlàáfíà fún wa ni ki a jowó ara wa fün Olórun àti ki a béèrè pé Kó wádìí wa, kokinse ohun ti a ro pé a jé, tabi ohun ti àwon èniyàn ro pé a jé, tabi ohun ti a gbà gbọ́ pé a jé tabi a yóò fẹ́ràn láti jé, sugbon, “Wádìí mi, O Olórun, ṣàyẹ̀wò mi bí mo se wa ní ojú Rè.”
Ìbéèrè Ijiroro: Kí ni ìṣubú aláṣẹ bóofẹ́bóokọ̀ tọ́ka sí nípa ijáfáfá àlàáfíà to wa fi ipá lori àwon èniyàn? Kí ni Ìtàn kó mi nípa igbìyànjú àwon èniyàn láti sedá àlàáfíà?
Awọn Àyọlò Òrọ̀ ti a mu Láti Iṣẹ́ Takuntakun Olórun Àti Sáyẹ́nsì Òrọ̀-Inúọkàn Ti Bíbélì, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.
More
A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org