Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Ọjọ́ 27 nínú 30

Sátánì ko dúró fún sisé àwon ohun àìtọ́ nínú Bíbélì: ó jẹ́ èdá tó burú. Àwọn ènìyàn ni okùnfà isé àwon ohun àìtọ́, àtipe won sé ohun àìtọ́ nítorí èrò àìtọ́ ínú won. Ona iwahihu ọgbọ́n àrékérekè ti é̩dá wa mu wa dá ẹ́bi fún Sátánì nígbà tí a mo ni pipé wipé ó yẹ kí a dá ara wa lẹ́bi; ni òtìtó ẹ́bi fún ẹ̀ṣẹ̀ wà ni èrò àìtọ́ ínú wa.

O lè jẹ́ pé Sátánì n bínú púpò bí Èmí Mímó nígbà tí àwọn ènìyàn ṣubú si ẹ̀ṣẹ̀ òde ara, sùgbón fun ìdí to yàtọ̀. Nígbà tí àwọn ènìyàn ba wó ẹ̀ṣẹ̀ òde ara won si fa idaamu si ayé won, Sátánì mo délẹ̀délẹ̀ wipé won ma fé Alákòóso mìíràn, Olùgbàlà àti Olùdáǹdè; bí o jé pé Sátánì le fi àwọn ènìyàn sínu àlàáfíà àti ìṣọ̀kan àti ìbámu yàtọ̀ si Olórun, o ma sé bẹ́ẹ̀ (wo Lúùkù 11:21-22).

Ìbéèrè Ijiroro: Tani mo dá lẹ́bi fún èsè mi? Kí ni Sátánì jèrè ti mo bá gbé ìgbé-ayé to ìdúróṣinṣin àti ti ìwà rere? Kí ni o pàdánù ti mo bá sé báṣubàṣu ti mo mọ̀ pé mo ní-lò àlàáfíà yàtọ̀ si ìsapá mi?


Àwọn Àyọlò Òrọ̀ ti a mu Láti Sáyẹ́nsì Òrọ̀ - Inúọkàn Ti Bíbélì © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 26Ọjọ́ 28

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.

More

A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org