Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ
Awa n wàásù fáwọn ènìyàn bíi pé won mọ̀ pé àwọn jé ẹlẹ́ṣẹ̀ to ń kú lọ, sùgbón won ko mò. Won ń ni ìgbà dáradára, àtipe gbogbo àsọyé wa nípa iní-lò láti di atúnbí wa láti àgbègbè ìkápá ti wón ko mò ohunkóhun nípa; nítorí àwon ènìyàn gbìyànjú láti rì ibanuje sínú fàájì ayé kò tẹ̀ lé gbogbo ohun bíi ti yen. Kosi ohunkóhun to fa ènì mọ́ra nípa Ìhìnrere si ènìyàn lasan; ènìyàn kan ṣoṣo ti Ìhìnrere fa mọ́ra ni ènìyàn to ni ìdánilójú ẹ́ṣẹ̀.
Yàtọ̀ si ìmò Jésù Kristi, àti yàtọ̀ si wiwá ni rirún nípasẹ̀ ìdánilójú ẹ́ṣẹ̀, ènìyàn ni èrò to fi wón si ayò àti àlàáfíà pípé. Ìdánilójú ẹ́ṣẹ̀ máa wá nípasẹ̀ Èmí Mímó ti ń wọlé nítorí ẹ̀rí-ọkàn wa ti wa ni láìjáfara láti wò ìlànà Olórun.
Ìbéèrè Ijiroro: Iru ìhìn iṣẹ́ àlàáfíà wo ni mo ni fún àwon ti ko mò pè àwon je àjèjì sí Olórun? Kí nìdí ti Ìhìnrere ko fa àwon to fẹ́ràn bóṣe wa mọ́ra? Báwo ni àánú Olórun se mú mi mò iní-lò mi fún un?
Àwon Àyọlò Òrọ̀ ti A Mu Làti Ìlànà Ìwà Híhù Ti Bíbélì, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.
More
A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org