Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ
Nìgbàti Olórun bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ Rè nínú wa Kò ni ṣe iyàtọ̀ ńlá nínú ìgbésí ayé òde wa, sùgbọ́n Ó yí Ibùdó ìdánilójú wa. Dípò ki a gbára lé ara wa àti àwon ẹlòmíràn, a gbára lé Olórun, àtipe wọ́n pa wa mó sínú àlàáfíà pípé. Gbogbo wa lomọ̀ iyàtọ̀ tó se ti a ba ni igbàgbọ́ nínú enìkan to ni igbàgbọ́ nínú wa àti enì ti àwa gbà gbọ́ nínú rè. Kò ṣeé ṣe láti wa ni ìtẹ̀mọ́lẹ̀. Ayé gíga naa kií se pé a ni igbàgbọ́ fun nǹkan kan, sùgbọ́n nìgbàti a ba gbógun ja àwon ohun ní ìṣòro tabi ní ìtẹ̀sí-ọkàn wa, a maa rí gbogbo igbàgbó wa lé olá Jésù Kristi.
Kí àlàáfíà Olórun sọ wá di mímọ́ pátápátá kí áma ba jé ọkàn aláàárẹ̀ ton fa ifasẹhin si ètò Rè, ṣùgbọ́n wíwá ni pípé nípasẹ̀ ìjìyà. pátápátá
Ìbéèrè Ijiroro: Báwo ni ipò mi nínú Kristi se mú mi kúrò làti wà ni ìtẹ̀mọ́lẹ̀ nípa aáwọ̀? Báwo ni àlàáfíà Olórun se fún mi láàyè láti jẹ́ pípé nípasẹ̀ ìjìyà?
Awọn Àyọlò Òrọ̀ Ti A Mu Làti Ìtẹ́wọ́gbà Si Olórun àti Iṣẹ́ Takuntakun Olórun, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.
More
A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org