Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Ọjọ́ 19 nínú 30

Awon ohun daradara wa nipa Imole, sugbon awon ohun ti o dara mbe pelu. Nigbati Imole Emi Olorun ba wonu okan ati aye eni to ni ayo ati alafia pipe laisi Olorun, koni rorun fun iru eni be, Imole mamu idamu ati wahala. Ti imole ba wole gbogbo ohun okunkun ma teriba. Ohun okunkun orile ede ma tuka, kokinse nipa oju lila sugbon nipa arakunrin ati arabirin tiwon je eleri nitoto si Olorun.

Olorun mma lo oju gege bi eri okan fun enia ti ati mu duro ninu Emi Mimo. Ti aba rin ninu Imole gege bi Olorun sen mbe ninu Imole, ti a si te oju wa Le e, die die ati nitoto gbogbo iwa wa ma bere sini wa ni igbese aye daradara atipe gbogbo nnkan laye enia na ma wa ni irele, isokan ati alafia.

Ibere Ijiroro: Kini Imole Olorun fihan si o tio da o loju ru, mu e binu abi tiko ye o? Bawo ni titeju le Oluwa mase mu gbogbo ohun ti o sokunkun wa sinu Imole alafia ati isokan?

Amu iwe lati Mo ran ati kika oro Olorun lori apata © Discovery House Publishers

Ìwé mímọ́

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.

More

A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org