Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ
Orundun Ogun ti koja sehin niwon Jesu, Alade Alafia, wa saye gbogbo angeli kede alafia sori aye. Sugbon Alafia no da? Majemu tuntun kowipe awon angeli sotele nipa alafia; won kede alafia- alafia fun awon eniyan nipa ifaradara si Olorun. Jesu wa lati fihan wipe Olorun mbe pelu awon eda ati nipase Re ale so enikeni di omo Olorun ni illana Jesu Kristi. Eyi ni Ifihan awon Kristeni.
Awon towa lona otito na ni aworan alagbara tojomo ti Jesu, alafia Re sami siwon ni ona alapapo tikose fojuri. Ina aro tan soju won, ayo ainipekun mbe lokan won. Ibikibi tiwon balo, inu awon eyan dun tabi won wo san tabi muwon mo nipa ilo ohun pataki.
Ibeere òjìji: se sami alafia Kristi? Ona wo ninmo gba dasi alafia ti Kristi kede? Ona wo ninmo gba di ikede na lowo lati wa si imuse?
Amu awon oro yi lati Ibi Iranlowo ©Alakede Ile Awari

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.
More
A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org