Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ
Nigbati aba se àpérò pelu Jesu kristi lori aye awon ẹlòmíràn gbogbo kàyéfì ma kuro, nitori koni kàyéfì, atipe àníyàn wani lati gbe inu Re. Eje ki ani igbóyà ninu Imo Re ati nitótó wipe gnohno ohun yo dara. “O je olódodo; nitori kole sé ara re” (2 Tim. 2:13). Orin awon angeli’ síbẹ̀ je òtítọ́: “Ogo nifun Olorun loke orun, ati àlàáfíà fun aye si awon eda Tose anu fun.”
Ona àlàáfíà àtinúwá mbe ninu ohun gbogbo lati wa ni ibamu si ìgbádùn ati ìwà ti ife àtọ̀runwá. Iru eyi ti yoo ni ohun gbogbo ti o ṣe aṣeyọri ati pe o ṣe gẹgẹ bi ifẹ ti ara wọn, won kò lati mo ona yi,nítorí náà dari si aye to le koko ati ìkorò, nigbagbogbo kòsi ísinmi tabi erin, lai tẹ ọna àlàáfíà to bára mu ni ibamu niẹ̀kúnrẹ́rẹ́ si ife ti Olorun.
Awọn Ìbéèrè Ijiroro: Àwọn kàyéfì wo ni o yọ àlàáfíà mi lẹ́nu? Awọn àpèjúwe ti alaafia wo ni mo n reti lati ọdọ awọn ẹlomiran ti emi kò mùra tán lati se? Ninu awọn ọna wo ni mo gbọdọ wa ni ibamu si Ìdùnnú Ọlọrun?
Amu awọn ọrọ lati Ékò Kristeni, © Olùtẹ̀jáde Ni Ile Awari

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.
More
A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org