Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ
Ipadabo Jesu Kristi kinse ohun alafia. Oje oun tin bani leru. oun alagbara. Se motisetan kia bimi si ijoba ti Jesu Kristi wa? Tobaribe mogbodo mura fun ijakadi ni gigun ni ijoba timo wa niyi. Ofin toya Olorun ati eniyan gbodo pora, iwole Jesu Kristi tumọ si ijakadi nipa ọna ti mo ti n wo awọn nkan. Gbogbo ohun gbogbo ma yikodo. Alafia atijo ati ilana atijo gbodo lo, ati pe akole gba ipele atijo na pada atipe a ko le pada si alafia lori ipele ti atijọ.
Nigba ti satani mba ṣakoso awọn ọkàn ti awọn eniyan lasan labẹ imisi ti eṣu, wọn ko ni wahala, wọn ma ni alaafia, ti a wọ ni ibi mimọ (cf Orin Dafidi 73), ati pe ki Ọlọrun to le ṣe akoso ijọba eniyan, O gbọdọ kọkọ gbe ofin eke ṣubu na.
Awọn Ìfẹnukò Ìdánilẹkọ. Kini awon ohun tin bani leru timo gbodo la koja kin tode alafia? Kini ìdààmú to pọn dandan lati bori ilana atijo? Kini ofin eke togbodo bì ṣubú.
Amu awon oro yi lati inu Omo odo bi Oluwa re © Alakede Ile Awari

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.
More
A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org