Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ
Oun todara ni lati ye oju emi wa wo, lodo olùtöjú celestial, lati fojusi ona tongba lati tun oju wa se, oni eleri oye ti Jesu seleri funwa, oun ni ebun alafia E. Kosi bi ayidayida na seleto, ipade kan pelu Jesu faramọ na masalo, ijaya na malo, gbogbo ofifo aijinile malo nigbana ni alafia E yo wole, ifokanbale tikolopin, nitori ohun toso" gbogbo agbara lati fifun mi."
Oh, ni ekun alafia, ayọ ati idunu taba gba wipe kosi ohun tole yawa pelu ife Olorun, ton be ninu Jesu Kristi Oluwa wa.
Ibere ijiroro: Bawo ni Olorun ti ye oju wa wo ati tun oju emi wa se? Kini mon ri to han kedere nisiyin? Bawo ni ohun to han kedere se mu ifoya ati faramọ kuro?
Amu awon oro lati Mo Si Ran Yin ati Ife Olorun ©Alakede Ile Awari

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.
More
A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org