Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ
Ti aba Moo nipase itoni atonrunwa E, pelupe titele Re funwa ni isimi. Igba ati akoko ma di kan wonyosi sonu ninu ibasepo pataki yi. Uroopo yi konkinse ni asiri, sugbon ni pipé aṣayan iṣẹ-ṣiṣe, kokinse ni alafia to diro sojukan sugbon nipa isimi toni itesiwaju pipe.
Asiri gidi ni emi eniyan nipe ninu akoko to kun fun wahala nla eniyan ma foju koju oun tiko fara si tele nigba toni alafia, melo ninu wa lo damu nipa ipo okan eniyan si Olorun? Sibe awon ohun yi lonfa inu bibi si okan Olorun, kokinse awon ija ati ijakule ton mu inu bibi si okan wa.
Awon Ibeere Ijiroro: Bawo ni “ alafia toni itesiwaju pipe ” sedayato pelu “alafia toduro soju kan”? Awon ona wo ni alafia awujo ati alafia oselu seje ota si alafia pelu Olorun.
Amu awọn ọrọ lati orisirisi eko ati imo Kristeni © Alakede Ile Awari

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.
More
A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org