Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Ọjọ́ 8 nínú 30

Ise òwò to rorun ni iwàásù, oje ohun tiń dáyà foni to rorun lati sofun awon iyoku ohun tinwon yo se; o jẹ ohun miran lati jẹ ki ìhìn rere Ọlọrun yipada si itapadà. “O ti nkọ awọn eniyan wọnyi pe kiwon kun fun àlàáfíà ati ayó, sugbon iwo tikalara e nko? Nje okun fun àlàáfíà ati ayọ̀?” Ẹlẹri otitọ ni ẹniti o jẹ ki imọlẹ rẹ tan ninu awọn iṣẹ ti o fi ifara Jesu hàn; eni ti o ngbe ni otitọ gege bi o ti wàásù rẹ.

Ọnà ti aye Ọlọrun fi ara rẹ hàn ni ayọ ninu àlàáfíà ti ko ni ifẹ fun ìyìn. Nigbati èèyàn ba so ìhìn rere ti o mo pe ti Ọlọrun ni ìhìn rere na, ẹri si imuṣẹ ìdí ti a ṣẹda ni a o fúnni lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, àlàáfíà Ọlọrun ma tẹ̀dó, ọ́kùnrin toso ìhìn rere na ko bìkítà fun boya ìyìn tabi ibáwí lati odo enikeni.

Ìbééré ìdánilékoo: kini awon ohun ti nmo wàásù jú awon ohun ti nmo ń ṣe lo? Nje ìforígbárí aláìyiyanjú mbe laarin emi ati eni kan todabi iboji ti nbo ina Kristi ninu mi? kí ni igberaga na ti n mumi ma wa ni àlàáfíà pelu eni na?

Amu owon oro lati Ife Ti Olorun© olùtẹ̀jáde Ile Awari

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 7Ọjọ́ 9

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.

More

A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org