Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ
Awọn ọjọ́ wo ni o túbò mu o te síwájú sí i ni ìmọ̀ Olórun —àwon ojó ti ìtànṣán oòrùn ati àlàáfíà ati aásìkí? Láéláé! Àwon ojó ti ìpọ́njú, àwon ojó Ìdààmú, àwon ojó Ìyàlẹ́nu òjijì, àwon ojó igbati ilẹ̀ ayé ti àgọ́ ìjọsìn yi dààmú níbi tágbára e mọ,, àwon ojó wọ̀nyi nígbà o kọ́ ìtumọ̀ ìtara “Lo.” oríṣiríṣi àjálù ìṣẹ̀dá ayé—ikú, àrùn, ọ̀fọ̀—maa ji eniyan didé nígbàti kòsóhunkòhun to ma ji, atipe kole wa bakaánnà mo. A kole mo láé “àwọn ìṣúra òkùnkùn” bí a bá wa nígbàgbogbo ni ibi ààbò jẹ́jẹ́.
láìka gbogbo ọgbọ́n àìmọ́ wa, láìka gbogbo eré wa ati fifìfẹ́hàn si isé ti ilẹ̀ ayé, ati láìka gbogbo ọgbọ́n orí wa, ìgbẹ́kẹ̀lé kíkún ti ọgbọ́n Olórun ma wa lati dáàmú wa.
Ìbéèrè Ijiroro: Kí ni Ìdààmú kó mi nipa àlàáfíà? Ǹjẹ́ mo tẹ́wọ́gbà Olórun lati dabarú ayé mi tabi mo ti gbe àmì “E Má Damiláàmú” sori ìlẹ̀kùn ayé mi?
Awọn Àyọlò Òrọ̀ ti a mu lati Ìmọ̀ Ogbọ́n ti ẹ̀ṣẹ̀, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.
More
A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org