Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ
A wa n dín ara wa kù ati èròǹgbà wa nipa Olórun nípa gbigbójú fo apá ti Èdá Àtònruwá to ni iṣapẹẹrẹ nípase ọ́lọ́mọge, atipe Olùtùnú yi dajudaju je aṣojú apá Èdá Àtònruwá. Olùtùnú náà lo tàn ifé Olórun si ókàn wa káàkiri. Olùtùnú náà lo rìwa sínú ipapọ̀ pẹ̀lú Jésù, nínú èdè ìyàlẹ́nu ti Ìwé Mímọ́, odigba ti aba n gbé nípase ìsopọ̀ àràmàǹdà pẹ̀lú Olórun. Olùtùnú náà lo ma mu awon èso wonyi jáde wá èso bi ífẹ̀, Ìdùnnú, àlàáfíà, ìpamọ́ra, inú rere, dáradára, ìgbàgbọ́, ìwà jẹ́jẹ́, olọ́kàn tútù. Ìtọ́sọ́nà nipase ìbánikẹ́dùn E yọrí nípa ìbáwí ìbùkún sinu òye ti Olórun to kọjá ìmọ̀.
Oluwa, yo ídè ero yi, ati àlàáfíà ati ìmọ́gaara ati agbára. Kún mi ni ojó oni pẹ̀lú iwà pẹ̀lẹ ati àánú ati oore ọ̀fẹ́ E.
Ìbéèrè Ìdánilẹkọọ: Kí nìdí tí to fi ṣòro lati ni àlàáfíà pẹ̀lú Olórun ti a ba wa ni aáwọ̀ pẹ̀lú ẹ̀yà òdìkejì? Kí nìdí tí àlàáfíà nilo iwà pẹ̀lẹ bakanna bi agbára bakanna bi ìmọ́gaara ati àánú?
Awọn Àyọlò Òrọ̀ ti a mu lati Ibawi Kristiẹni ati kíkànilèkùn Ọlórun, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.
More
A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org