Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ
Ìròiyè inú ti àlàáfíà ni ìsomọ́ pélu àkópọ̀ ìwà ni pe gbogbo agbára wani pípè ton ṣiṣẹ́ ko baà lè dín iṣẹ́ ku. Iyẹn ni ohun ti Jésù túmọ̀ sí nigbati o sọ pe“Àlàáfíà Mi.” Mani lọ́kàn rara wipe Ìròiyè inú ti ìbànújẹ́ tabi ìpòkúdu wani ìsomọ́ pélu àlàáfíà. Ìleradídá ni àlàáfíà ará, ṣùgbọ́n ìleradídá kì í ṣe ìpòkúdu; ìleradidá ni ìjẹ́pípé ti iṣẹ́ ará. Ìwà funfun ni ìwà rere àlàáfíà, ṣùgbọ́n ìwà funfun kì í ṣe aláìlẹ́ṣẹ̀; ìwà funfun ni ìjẹ́pípé ti ìwà rere ará. Wiwa ni mímọ́ je àlàáfíà nípa tẹ̀mí, ṣùgbọ́n ìjẹ́mímọ́ kì í ṣe ìdákẹ́jẹ́ẹ́; ìjẹ́mímọ́ ni fifìfẹ́hàn si iṣẹ́ ti ẹ̀mí.
Imọ̀ Olórun to jinlẹ̀ mamu o wa ni àlàáfíà ti kò ṣeé fẹnu so ti kó dáńgájíá lati ni ìmọtara -tara ẹni nikan.
Ìbéèrè Ijiroro: Ònà wo ni jíjókòó tẹtẹrẹ n gba funi ni làákàyè ayédèrú àlàáfíà? Kí ni di ti iṣẹ́ fi nílò àlàáfíà? Kí ni di ti fifìfẹ́hàn -tara ẹni nikan se ni ìpín nínú àlàáfíà?
Awọn Àyọlò Òrọ̀ ti a mu lati Mimú Àwọn Ọmọ wọnú Ògo ati Aímọ Ibo, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.
More
A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org