Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Ọjọ́ 5 nínú 30

Àwọn ọmọdé nígbà míràn man fòyà nínú òkùnkùn. Èrù ma sawo ínú ọkàn wọ́n ati iṣan ara atipe wọ́n wo ipò to kàmàmà; nígbà náà wọ́n si gbó ohùn bàbá tabi ìyá, gbogbo ohun ma wa ni irẹlẹ àtipe wọ́n si lo sun. Nínú irírí tẹ̀mí wa oje ìkaánnà. Àwon Jìnnìjìnnì wa sojú-ọ̀nà làti pàdé wa átipe ọkàn wa ma gbọ̀n pẹ̀pẹ̀ pélù èrù to kàmàmà; nígbà náà a wa gbó ìpè orúko wa, ohùn Jésù ton so wí pé, “Émi ni, mase bèrù,” àti álàáfíà Olórun to kojá óye ma jogún okàn wa.

Ènìyàn kò lè wà ba kan náà mo láé nígbà ti o ba gbó wàásù Kristi. Ó le so wí pé oun ko fetí sí wàásù náà; ó le dabi wípè o ti gbàgbé gbogbo ohùn nípa re, sugbon ko ri ba kan náà mo, átipe ni nígbàkigbà òtító le rú sòkè sínú ìmọ̀lára rè tó ma run gbogbo álàáfíà áti ayò re.


Ìbéèrè Ijiroro: Kí ló n jámi láyà? Ígbà wo lo ṣeé ṣe ki ni Ibèrù ju? Órọ̀ Jésù wo lo man fa ìdágìrì fu mi? Órọ̀ Jésù wo lo mú Ibèrù kúrò?

Awọn Àyọlò Òrọ̀ ti a mu lati Ìránṣẹ́ bi Olùwa E Ati Sá Eré Ìje Òni, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.

More

A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org