Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Ọjọ́ 2 nínú 30

A nsọ̀rọ̀ nipa “ipò toje wipe a ko ni iṣakoso lori won.” Ko si enìkan ninu wa ti o ni iṣakoso lori awọn ipò e, ṣugbọn a ni ojúṣe fun ọna ti awa ngba wakọ̀ wa larin awọn nkan bi wọn ṣe jẹ. Okọ̀ ojú-omi méjì lema tukọ̀ ìrìn àjò won ni ìtọ́sọ́nà to yàtò ninu afẹ́fẹ́ ìkaánnà, ni ìbámu pẹ̀lú òye awakọ̀ na. Awakọ̀ na to ń darí ọkọ̀ ojú omi re losi òkúta o wí pé ko le ran o, afẹ́fẹ́ wa ninu ìtọ́sọ́nà yẹn; ẹniti o mu okọ̀ ojú-omi e wonu èbúté ni afẹ́fẹ́ kaánnà, sugbon o mo bo ṣe le ge awọn tukọ̀ e ki afẹ́fẹ́ lẹ́fẹ́ ṣi itọsọna ti o fẹ. Agbára àlàáfíà Olórun ma ràn ọ́ lọ́wọ́ lati tukọ̀ ọ̀nà e ni ṣàmúlùmálà lásán ti ayé.

Oluwa, si Ọ ni mo yipada, si Ọ. Moje aláìrílégbé titi ti E ma fi àbò àlàáfíà Yin kan mi, dídùn làákàyè ifẹ́ Yin.

Àwọn Ìbéèrè Ijiroro: Agbára wo ni àlàáfíà ni ni ayé mi? Njẹ Mo jà àlàáfíà lólè nipasẹ itẹnumọ mi wipe ki o tẹriba fun“ làákàyè to wọ́pọ̀” mi? Kilo n túbọ̀ funi ni àbò jú wíwà nínú àlàáfíà pẹ̀lú Olórun to nífẹ̀ẹ́ enì?

A yo áwọn oro wonyi lati Ìpìnlẹ̀ Ìwà Rere Ayé ati kikanlẹ̀kùn Olórun, © Olùtẹ̀jáde Ile Awọn Awari

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 1Ọjọ́ 3

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.

More

A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org