Ìrìn àjò lo si Ìbùje EranÀpẹrẹ

Journey To The Manger

Ọjọ́ 12 nínú 70

Fifèsì sí Olórun

Ìdánaàdéhùn ìgbéyàwó Màríà àti Jóséfù jé bóyá ohun ti àwon ebí ti gbádúrà nípa fún ojó típé. Àwon méjèèjì wá láti ìran Oba Dáfídì— ìdógba tó jé pípé tó má ti fún àwon ebí méjèèjì nídí láti yo ayò. Àmó lójijì Olórun sèdíwó ayeye wón.

Ìyárakánkán ìlà ìdílé ángèlì sínú ìtàn Màríà kò fún ní àkókò láti gbára dí fún isé rè: Ó bá ojú rere Olórun padè àtipe ó má bí Omo Rè—bó ti lè jé pé wúndíá ni. Ó gbódò ti nírírí ìmólarà olójú ọ̀gbàrá— yàtò sí ìyalenu rè, àwon èrò ohun ti ebí è àti àwùjo má rò má ti dà sínú okan rè. Màríà ni láti pinnu: Se òun má jọ̀wọ́ ara rè sílè sí ètò Olórun, èyí tó dâ bí pé kò seé se àtipe ó ñ baní lèrù lórí oréfèé lásán?

Ìdáhùn Màríà onígboyà àti alágbára se ipa ònà fún gbogbo onigbágbó. Nígbà tí a bá jọ̀wọ́ ara sílè sí àwon ìdíwó Olórun, a lè simi ni ìmò pé nígbà gbogbo Loni ète tó ga jù fún ayé wa.

Ìse Sisé: Bí ebí, e se ìwádìí bí àwon onírúurú àsà ñse sájọyò Kérésìmesì. Sàgbéyèwò ìtéwó gbà àwon ìsìn tuntun.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 11Ọjọ́ 13

Nípa Ìpèsè yìí

Journey To The Manger

Ní alẹ́ ìdákẹ́ rọ́rọ́ kan ní ọdún 2000 sẹ́yìn, àwọn angẹli mu ìròyìn ìbí Olùgbàlà wá fún ẹgbẹ́ àwọn daran-daran kan níbi tí wọn ti ń da ẹran wọn. Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ìròyìn náà, àwọn daran-daran wọ̀nyí fi ohun gbogbo sí'lẹ̀ láti wá ìkókó tí ó wà ní ibùjẹ ẹran ní Bẹtilẹhẹmu. Lẹ́yìn gbogbo àwọn ọdún wọ̀nyí, ìpè yìí kò tíì yí padà. Ẹ̀ bá Dr. Charles Stanley rìn bí ó ṣe ń ràn yín l'ọ́wọ́ láti súnmọ́ Olùgbàlà, àti láti mú ọkàn yín le láti wá àyè láti sinmi nínú ìfẹ́ Bàbá ní àkókò yíì. 

More

A fé láti dúpé lówó Isé òjísé Touch fún ìpésé ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí, E jòó ṣèbẹ̀wò visit: https://intouch.cc/yv18