Jésù: àsíá Ìṣẹ́gun wa

Ọjọ́ 7
Nígbà tí a bá ń ṣe ayẹyẹ ajinde, à ń ṣe ayẹyẹ ìṣẹ́gun tí ó ga jùlọ nínú ìtàn. Nípa ikú àti ajinde Jésù', ó borí agbára ẹ̀ṣẹ̀ àti isà òkú títí láí, àti gbogbo ohun àbájáde wọn, ó sì yàn láti pín ìṣẹ́gun náà pẹ̀lú wa. Ní ọ̀sẹ̀ ayẹyẹ yii, jẹ́ kí á wọ inú díẹ̀ nínú àwọn odi agbára tí ó ṣẹ́gun, ṣe àṣàrò lóríi ìjà tí ó jà fún wa, kí o sì yìín gẹ́gẹ́bíi àsíá ìṣẹ́gun wa.
A fẹ́ láti dúpẹ́ lọ́wọ́ ọ ìjọ ti àwọn ilẹ̀ gíga fún pípèsè ètò yí. Fún ìsọfúnni síi, jọ̀wọ́ ṣe àbẹ̀wò:https://www.churchofthehighlands.com
Nípa Akéde