Ìwé Iṣe Awọn Aposteli

Ìwé Iṣe Awọn Aposteli

Ọjọ́ 28

Ètò ẹ̀kọ́-kíkà ẹsẹ̀-Bibeli-kan-lójúmọ́ yìí jálẹ̀ ìwé Iṣe Awọn Aposteli tẹ̀lé ìrìn-àjò àwọn ọmọ-lẹ́yìn Jesu lẹ́yìn ìgòkè rẹ ọ̀run Rẹ̀. Ṣàwárí bí a ti bẹ̀rẹ̀ ilé-ìjọ́sìn, bí a ti fún àwọn ènìyàn Ọlọrun lágbára nípasẹ̀ Ẹ̀mí Rẹ̀, bí àwọn ọmọ-lẹ́yìn Jesu ṣe farada ìdánwò àti inúnibíni, àti bí ọ̀pọ̀ ènìyàn ṣe wá láti gbọ́ ìròyìn rere ti ìfẹ́ Ọlọrun. YouVersion ni ó ṣàgbékalẹ̀ ètò yìí.

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Mount Zion Faith Ministry fún pípèsè ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí i, jọ̀wọ́ lọ sí: https://mountzionfilm.org/

Nípa Akéde