Ìrìn àjò lo si Ìbùje EranÀpẹrẹ

Journey To The Manger

Ọjọ́ 17 nínú 70

Olórun Rí Jù Lo

Òpò lára wa lè rò pé tí Jésù bá wá sáyé lónìí, Ó má yàn ebí tí ìrísí rẹ̀ jọjú, tó kàwé, fáa fún láti dàgbà pèlú—àti kéde ìròyìn ológo tí ìbí Rè sí a sàyàn egbé àwon oníwàásù lókìkí. Síbè òdodo ìtàn Kérésìmesì fi hàn ìyàtò láàárín ìran Olórun àti àwon ìlànnà tí ayé wa. Lónìí, a lè tí bí Jésù sódó afági tón sisé kára sínú àdúgbò olówó póókú àti obìnrin àfésónà. Àtipe bóyá àwon àngélì lè ti farahàn sí egbé àwon tó ti sèwòn rí nínú isé adàgùn, tí wón sisé lèyín láti parí Isé ìgbélè kòtò.

A sábà máa ń gbàgbé bí Màríà àti jóséfù se jìnnà sí èyíkéyí òkìkí awújò àti bí a se wo àwon olùsó àgùntàn bí àìmò àti aìse fokàn tán nípa ìlànnà Júù. Ènì kòòkan tó ogunlógo kárí ibùje eran ’ Jésù ní alé òru tí kò láfiwè nírírí ìko sílè àti ìpínyà. Síbè àwon èyí jé èèyàn pàtàkì tí Olórun yàn láti nírírí oókan lára ìsèlè tó jé mímó jù lo ni ìgbàkígbà. Ó rí okàn wón àti ìníyelórí tòótọ́ gangan—kódà nígbà tí kò sí enikéni tó rí.

Activity: Kó àwon òré kan Jo pò àti gbóúnje ní agbègbè ìbúgbé aláìrílégbé.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 16Ọjọ́ 18

Nípa Ìpèsè yìí

Journey To The Manger

Ní alẹ́ ìdákẹ́ rọ́rọ́ kan ní ọdún 2000 sẹ́yìn, àwọn angẹli mu ìròyìn ìbí Olùgbàlà wá fún ẹgbẹ́ àwọn daran-daran kan níbi tí wọn ti ń da ẹran wọn. Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ìròyìn náà, àwọn daran-daran wọ̀nyí fi ohun gbogbo sí'lẹ̀ láti wá ìkókó tí ó wà ní ibùjẹ ẹran ní Bẹtilẹhẹmu. Lẹ́yìn gbogbo àwọn ọdún wọ̀nyí, ìpè yìí kò tíì yí padà. Ẹ̀ bá Dr. Charles Stanley rìn bí ó ṣe ń ràn yín l'ọ́wọ́ láti súnmọ́ Olùgbàlà, àti láti mú ọkàn yín le láti wá àyè láti sinmi nínú ìfẹ́ Bàbá ní àkókò yíì. 

More

A fé láti dúpé lówó Isé òjísé Touch fún ìpésé ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí, E jòó ṣèbẹ̀wò visit: https://intouch.cc/yv18