Ìrìn àjò lo si Ìbùje EranÀpẹrẹ
Ìfihàn Okàn Olórun
Fi tì sẹ́gbẹ̀ẹ́ kan fún ìgbà díè gbogbo ìdí tí ẹlẹ́kọ̀ọ́ ìsìn tó ṣàlàyé ìdí tí Kristi se wá sáyé, àtipe ronú nìkan nípa ifé ńlá Olórun fún ó. Ó féran è gidigidi tó jé pé Ó fi Ògo Rè àti olá Rè tì sẹ́gbẹ̀ẹ́ kan láti dí Emánúẹ́lì, Ènì tó ń rìn pèlú è. jíròrò pé gbogbo nñkan láti bèèrè —láti Ogbà Édẹ́nì sí isé Rè ní ayé rè—a sún àti sèdá wón nípa ifé.
Ifé sún U láti farahàn sí opó onírèlè Téńpìlì tó gbádúrà fún ọdún lèyín ọdún fún bíbò Rè. Nínú ifé, Olórun sàtúntò ìtòlẹ́sẹẹsẹ Rè kí Ó lè bá òpò ènìyàn tí ó ṣiṣẹ́ ìránṣẹ́ fún àti wòsàn pàdé. Àtipe nínú ifé tó jé pé Ó jeun pèlú àwon elésè àti àwon agbowó òde àjèjì. Àwon tí awújò patì si apakan, Ó kó wón jo pò ní apá Rè. Ayé rè jé ifé ní ìgbésè.
Jésù fi okàn Olórun gangan hàn wa, ó ñ gbé pèlú wa àti ñ pèwá sí àjose, òtító tó jínlè pèlú Rè. Kò wá láti se òfin àti pa run àmó láti gbàlà àti pèsè ayé tuntun fún gbogbo ènì tó má wá sódó Rè.
Isé Sísé: Pè òré kan tí ó kò bâ sorò nígbà díè àtipe lo àkókò díè láti tún di ọ̀rẹ́ pa dà.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ní alẹ́ ìdákẹ́ rọ́rọ́ kan ní ọdún 2000 sẹ́yìn, àwọn angẹli mu ìròyìn ìbí Olùgbàlà wá fún ẹgbẹ́ àwọn daran-daran kan níbi tí wọn ti ń da ẹran wọn. Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ìròyìn náà, àwọn daran-daran wọ̀nyí fi ohun gbogbo sí'lẹ̀ láti wá ìkókó tí ó wà ní ibùjẹ ẹran ní Bẹtilẹhẹmu. Lẹ́yìn gbogbo àwọn ọdún wọ̀nyí, ìpè yìí kò tíì yí padà. Ẹ̀ bá Dr. Charles Stanley rìn bí ó ṣe ń ràn yín l'ọ́wọ́ láti súnmọ́ Olùgbàlà, àti láti mú ọkàn yín le láti wá àyè láti sinmi nínú ìfẹ́ Bàbá ní àkókò yíì.
More