Ìrìn àjò lo si Ìbùje EranÀpẹrẹ
Rántí Ènì Tó Jé
Olórun féràn ayẹyẹ ìrántí. Jákèjádò ìtàn Bíbélì, a rí I tíñ sámì àwọn ìsèlè tó se pàtàkì pèlú ère ìrántí—tàbí pipè fún àjọ̀dún òdọọdún, láti ìgbà kan pàtó láti se ìrántí ìgbà Tó fi agbára ìgbàlà ìyanu àti ifé hàn sí àwọn ènìyàn Rè.
Kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì láti sákíyèsí irú àwọn èyí?
Nítorí Olórun fé kí a rántí ènì Tó jé àti ohun Tó ti se fún wa ní ònà tó jínlè. Ó mò pé a ní láti nírírí òdodo pèlú àwọn méjèèjì yìí ara àti okàn láti lóye e nítòótọ́ ni kíkún.
Bí Kérésìmesì, àwọn onigbágbó ni àǹfààní láti se ìrántí àti sájọyò ìsèlè àgbàyanu tó yàtọ̀ sáwọn yòókù: nígbà tí Olórun gbé eran ara wò àti wá sínú ayé láti fi ònà láti padà sí òdò Rè hàn wa.
Isé Sisé: Kọ lẹ́tà oníṣìírí kan sí ènìkan ní ẹgbẹ́ ológun tó máa lo ọdún Kérésìmesì jìnnà sílé.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ní alẹ́ ìdákẹ́ rọ́rọ́ kan ní ọdún 2000 sẹ́yìn, àwọn angẹli mu ìròyìn ìbí Olùgbàlà wá fún ẹgbẹ́ àwọn daran-daran kan níbi tí wọn ti ń da ẹran wọn. Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ìròyìn náà, àwọn daran-daran wọ̀nyí fi ohun gbogbo sí'lẹ̀ láti wá ìkókó tí ó wà ní ibùjẹ ẹran ní Bẹtilẹhẹmu. Lẹ́yìn gbogbo àwọn ọdún wọ̀nyí, ìpè yìí kò tíì yí padà. Ẹ̀ bá Dr. Charles Stanley rìn bí ó ṣe ń ràn yín l'ọ́wọ́ láti súnmọ́ Olùgbàlà, àti láti mú ọkàn yín le láti wá àyè láti sinmi nínú ìfẹ́ Bàbá ní àkókò yíì.
More