Ìrìn àjò lo si Ìbùje EranÀpẹrẹ

Journey To The Manger

Ọjọ́ 5 nínú 70

Gbigbé Àwò Èèyàn Wò

Apá kan tó lókìkí jù lo ti iṣẹ́ àgbàyanu Michelangelo lórí ilé ìjọsìn kékeré ti òkè àjà ilé Sistine ni a pè ni Ìsèdá Ádámù. Ádámù jókòó lórí àpáta, nígbà tí Olórun, ń sáré lọ nínú òfurufú, gùn sí i ìka owó Rè síhà ènìyàn àkókó. Ádámù nawó síhà Olórun àti àwọn ìka owó tón nà jáde fẹ́rẹ̀ẹ́ kàn padè —sùgbón wón kò kàn ara wón.

Ìṣèyàtọ̀ àwòrán yìí pèlú ewà gbigbé àwọ̀ èèyàn wọ̀.: Olórun dí eran ara kí Ó bá lè má nìkan sún mó ìsèdá Rè, àmó tún gbé bí oókan lára wa, èkúnréré ènìyàn àti èkúnréré àtòrunwá. Gbòlóhún òrò “gbigbé àwọ̀ èèyàn wọ̀.” lèó bí òrò elétò àṣà èkó-ìsìn, àmó ó jé òrò tó dúró fún àjosepò tó ṣòro láti gbà gbọ́.

Jésù dí omo ìkókó, lèyín náà omodé, lèyín náà bàlágà, àti lèyín náà dàgbà di géńdé ọkùnrin,—kí Ó bá lè níbátan tímọ́tímọ́ pèlú wa ní gbogbo ònà. Kò sí ebo tá lè fi wé ti Rè.

Isé Sisé: Lo àkókò díè nìkan àdánidá. Ronú jinlè nípa bí ìgbé ayé Jésù ti ayé se mú U láti ni àjosepò pèlú è níbí tó wa gangan.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 4Ọjọ́ 6

Nípa Ìpèsè yìí

Journey To The Manger

Ní alẹ́ ìdákẹ́ rọ́rọ́ kan ní ọdún 2000 sẹ́yìn, àwọn angẹli mu ìròyìn ìbí Olùgbàlà wá fún ẹgbẹ́ àwọn daran-daran kan níbi tí wọn ti ń da ẹran wọn. Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ìròyìn náà, àwọn daran-daran wọ̀nyí fi ohun gbogbo sí'lẹ̀ láti wá ìkókó tí ó wà ní ibùjẹ ẹran ní Bẹtilẹhẹmu. Lẹ́yìn gbogbo àwọn ọdún wọ̀nyí, ìpè yìí kò tíì yí padà. Ẹ̀ bá Dr. Charles Stanley rìn bí ó ṣe ń ràn yín l'ọ́wọ́ láti súnmọ́ Olùgbàlà, àti láti mú ọkàn yín le láti wá àyè láti sinmi nínú ìfẹ́ Bàbá ní àkókò yíì. 

More

A fé láti dúpé lówó Isé òjísé Touch fún ìpésé ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí, E jòó ṣèbẹ̀wò visit: https://intouch.cc/yv18