Ìrìn àjò lo si Ìbùje EranÀpẹrẹ

Journey To The Manger

Ọjọ́ 10 nínú 70

Ifé Àìnípẹ̀kun

Ayé lówólówó báyìí kò fi béè yàtò sí èyí tí a bí Jésù sínú rè. Àìsimi òsèlú, ogun, ìdálóró, àti ìrora okàn jé ìsèlè òjoojúmó nígbà náà—gégé bí wón se wà nísinsìnyí. Àwon ènìyàn àkókò Rè ń wá àwon ohun kaánnà tí a ń wá lójú méjèèjì lónìí: àlàáfíà, ifé, ààbò, àti ìmólarà ète.

Jésù wá láti fára È hàn gégé bí ònà fún okàn ènìyàn láti nírírí àlàáfíà òtító, ìtélórùn, àti ifé tó pé títí láé. Enikéni tó tí gbé fún ìtélórùn tí ayé nìkan soso mò pé nígbà gbogbo ní ìmólarà ohun kì í pé títí. Pàápàá ìrírí ifé tó jé àgbàyanu jù lo tí ènìyàn kò lè kún àlàfo tinú lótító.

Ifé ipò àfilélẹ̀, tó ń té okàn lórùn tí Jésù wá láti fi hàn wa yóò jé titi wa nígbà tí a bá wé mọ́ O àti gbà èbùn òfé tí Ó fún wa. Àtipe nínú ifé Rè, nígbèyìn a rí ohun tí a ń fi ìgbà gbogbo wá.

Isé Sísé: Sayewo àwon ìnà Kérésìmesì láyíká ìlú pèlú àwon ebí è.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 9Ọjọ́ 11

Nípa Ìpèsè yìí

Journey To The Manger

Ní alẹ́ ìdákẹ́ rọ́rọ́ kan ní ọdún 2000 sẹ́yìn, àwọn angẹli mu ìròyìn ìbí Olùgbàlà wá fún ẹgbẹ́ àwọn daran-daran kan níbi tí wọn ti ń da ẹran wọn. Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ìròyìn náà, àwọn daran-daran wọ̀nyí fi ohun gbogbo sí'lẹ̀ láti wá ìkókó tí ó wà ní ibùjẹ ẹran ní Bẹtilẹhẹmu. Lẹ́yìn gbogbo àwọn ọdún wọ̀nyí, ìpè yìí kò tíì yí padà. Ẹ̀ bá Dr. Charles Stanley rìn bí ó ṣe ń ràn yín l'ọ́wọ́ láti súnmọ́ Olùgbàlà, àti láti mú ọkàn yín le láti wá àyè láti sinmi nínú ìfẹ́ Bàbá ní àkókò yíì. 

More

A fé láti dúpé lówó Isé òjísé Touch fún ìpésé ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí, E jòó ṣèbẹ̀wò visit: https://intouch.cc/yv18