Ìrìn àjò lo si Ìbùje EranÀpẹrẹ

Journey To The Manger

Ọjọ́ 14 nínú 70

Pipàdé Jésù

Ronú nípa kàyéfì àwon olùsó àgútàn nígbà tí ángèlì Olúwa bá wón sòrò, lèyín náà òfurufú ti alé tó kún fún òpò ogun òrun pèlú ìmólè àti orin. Àtipe ronú wòye ìrusókè ìmóríyá wón bí wón se fi pápá àti àgùntàn wón le láti wá gbogbo ohun tí ángèlì tí sò fún wón nípa lo.

Síbè òpò ìrírí tó n sàyípadà ayé ènì jù tí wón ní alé náà ní pipàdé Mèsáyà lójúkojú. Ó mú okàn wón láti se ìjọsìn. Àwon ángèlì sò fún àwon olùsó onírèlè ti ń ṣètọ́jú àgùntàn ènì tí Omo ìkókó náà nibi tí wọ́n tọ́jú àwọn ẹran jé àti okàn wón tó retí jé kí wón mò pé Òun ni àti bólá fún àti wón si fi ìjúbà tó ye fún Un gégé bí Oba.

Bákan náà, nígbà tí o bá Jésù pàdé àti rí I fún ènì tó jé, mímò ifé Rè àti ògo máa kún okàn è pèlú ìdúpẹ́ àti mú o fé mò dáa dáa.

Isẹ́ Síṣe: Se àtòko àwon orin ìsìn Kérésìmesì tàbí àwon orin ìjọsìn tó fẹ́ràn jù. Bí ó ń se lo àkókò láti fetí sí i, ronú lórí ifé Olórun tó wá pọ̀ lápọ̀jù fún è.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 13Ọjọ́ 15

Nípa Ìpèsè yìí

Journey To The Manger

Ní alẹ́ ìdákẹ́ rọ́rọ́ kan ní ọdún 2000 sẹ́yìn, àwọn angẹli mu ìròyìn ìbí Olùgbàlà wá fún ẹgbẹ́ àwọn daran-daran kan níbi tí wọn ti ń da ẹran wọn. Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ìròyìn náà, àwọn daran-daran wọ̀nyí fi ohun gbogbo sí'lẹ̀ láti wá ìkókó tí ó wà ní ibùjẹ ẹran ní Bẹtilẹhẹmu. Lẹ́yìn gbogbo àwọn ọdún wọ̀nyí, ìpè yìí kò tíì yí padà. Ẹ̀ bá Dr. Charles Stanley rìn bí ó ṣe ń ràn yín l'ọ́wọ́ láti súnmọ́ Olùgbàlà, àti láti mú ọkàn yín le láti wá àyè láti sinmi nínú ìfẹ́ Bàbá ní àkókò yíì. 

More

A fé láti dúpé lówó Isé òjísé Touch fún ìpésé ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí, E jòó ṣèbẹ̀wò visit: https://intouch.cc/yv18