Ìrìn àjò lo si Ìbùje EranÀpẹrẹ

Journey To The Manger

Ọjọ́ 15 nínú 70

Mú láti wá

Ní àkókò ìbí Kristi, ìràwo tuntun títànyòò farahàn ní àwon òrun. Ìmólè rè náà lágbára tó jé pé o fà àwon afìràwọ̀mòye láti gbéra lórí ìrìn àjò tó jìnnà láti ṣàwárí Oba tí à tí sàsọtẹ́lẹ̀ bíbò Rè. Àwon okùnrin jé onímò ńlá láti ilà oòrùn tí Ásíà tí wón tí lo ayé wón ní wíwá ìmòye gégé bí onímọ̀ ọgbọ́n orí, ásíà, àti àwòràwo. Síbè, ní gbogbo wíwá témí wón, wón poúngbe fún púpò sí i.

wón fé fi ayé ìtùnú wón sílè àti isé ìgbésí ayé wón, ewu wa fún wón ni ohun gbogbo láti rìn ìrìn tó léwu nípasè àwon ipò ojú ojó tó gbóná janjan àti àwọn onírúurú àìmò. Àmó nítorí à tí gbà okàn wón mú láti owó àmì yìí pé à tí bí alágbára olúdáǹdè kan, wón wa di dandan fún un láti wà títí wón yóò fi rí I.

l

Bí àwon afìràwọ̀mòye, nígbà tí a bá wá lójúkojú pèlú Jésù, a lè fé pa ìmò èèyàn tì sẹ́gbẹ̀ẹ́ kan níwájú òye àìnípẹ̀kun Rè, jé kí a se ìjosìn ènì tí a ñ wá pèlú ìdùnnú.

Isé Síse: San síwájú! Nígbà mìíràn tó bá gbá ife kofí mú tàbí ṣètọ́jú, san-wó fún ènì tó wá lèyín rè lórí ìlà.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 14Ọjọ́ 16

Nípa Ìpèsè yìí

Journey To The Manger

Ní alẹ́ ìdákẹ́ rọ́rọ́ kan ní ọdún 2000 sẹ́yìn, àwọn angẹli mu ìròyìn ìbí Olùgbàlà wá fún ẹgbẹ́ àwọn daran-daran kan níbi tí wọn ti ń da ẹran wọn. Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ìròyìn náà, àwọn daran-daran wọ̀nyí fi ohun gbogbo sí'lẹ̀ láti wá ìkókó tí ó wà ní ibùjẹ ẹran ní Bẹtilẹhẹmu. Lẹ́yìn gbogbo àwọn ọdún wọ̀nyí, ìpè yìí kò tíì yí padà. Ẹ̀ bá Dr. Charles Stanley rìn bí ó ṣe ń ràn yín l'ọ́wọ́ láti súnmọ́ Olùgbàlà, àti láti mú ọkàn yín le láti wá àyè láti sinmi nínú ìfẹ́ Bàbá ní àkókò yíì. 

More

A fé láti dúpé lówó Isé òjísé Touch fún ìpésé ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí, E jòó ṣèbẹ̀wò visit: https://intouch.cc/yv18