Ìrìn àjò lo si Ìbùje EranÀpẹrẹ

Journey To The Manger

Ọjọ́ 20 nínú 70

Ìbí náà Jè ìbèrè

Ìhìn isé Kérésìmesì kò parí pẹ̀lú ọmọ ìkókó kékeré tó ń fi ọ̀já wé tó dulùbúlẹ̀ ni ibùgbé ẹran. A gbódò rántí ìdí tí a fi bí ọmọ náà. Ìhìn isé ẹkún réré Kérésìmesì ní pé Olórun ayérayé wá sí ilé ayé gégé bí ènìyàn láti gbà àwọn isèdá rèlà. Ọmọ ìkókó kékeré náà tí wọ́n fi ọ̀já wé wá fún ètè kan: O wá láti kú.

Àwọn ọwọ ìkókó tó sún àti ṣe ara wọn kúrò nínú ohun tí a fí wẹ wón themselves out of their wrappings within láàrín ohun tó ń fi fún ẹran loúnjẹ onígi tún jẹ́ àwọn owo káfíńtà kànna tí a kàn mọ́ àgbélébùú onígi gbágungbàgun. Àwọn ọwọ yìí kànna, bí tilè jé pé wọn ní ojú àpá, o róra sépo aṣọ ìsìnkú Rè tí a fí wé léyìn ìgbà tó borí ẹ̀sẹ̀ àti ikú kí O bá lé fún wa ní ìyè àìnípẹkun. Àti pé àwọn tún ní ọwọ kànnà tó tífétífé na ọwọ Rè gbé wa sókè lákàtúnkà jakejado ayé yìí rò le.

Ní àkókò Kérésìmesì yìí, nígbà tí o dàbí pé gbogbo nǹkan tẹtẹ àti yára kankan, má kò wọnú ìsíse àti àkójọpọ̀-ọ̀rọ̀.

Isé Ṣiṣé: Ṣe ohun kan pèlú ọwọ rẹ̀—káàdì, iyàwòrán, isé ọwọ—kí o sí fún ẹnìkan bí ẹ̀bùn láìgbèròtẹ́lẹ̀.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 19Ọjọ́ 21

Nípa Ìpèsè yìí

Journey To The Manger

Ní alẹ́ ìdákẹ́ rọ́rọ́ kan ní ọdún 2000 sẹ́yìn, àwọn angẹli mu ìròyìn ìbí Olùgbàlà wá fún ẹgbẹ́ àwọn daran-daran kan níbi tí wọn ti ń da ẹran wọn. Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ìròyìn náà, àwọn daran-daran wọ̀nyí fi ohun gbogbo sí'lẹ̀ láti wá ìkókó tí ó wà ní ibùjẹ ẹran ní Bẹtilẹhẹmu. Lẹ́yìn gbogbo àwọn ọdún wọ̀nyí, ìpè yìí kò tíì yí padà. Ẹ̀ bá Dr. Charles Stanley rìn bí ó ṣe ń ràn yín l'ọ́wọ́ láti súnmọ́ Olùgbàlà, àti láti mú ọkàn yín le láti wá àyè láti sinmi nínú ìfẹ́ Bàbá ní àkókò yíì. 

More

A fé láti dúpé lówó Isé òjísé Touch fún ìpésé ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí, E jòó ṣèbẹ̀wò visit: https://intouch.cc/yv18