Ìrìn àjò lo si Ìbùje EranÀpẹrẹ
Ó wá fún o
Bí a ñ see sájọyò ìbí Jésù ní àsìkò yìí, àjoyò tó ñ mbé ni okàn wa yé kó rọ̀gbà yí i káayíbírí láàárín ìdùnnú pé a féràn wa. Nípasè Jésù, okàn Olórun polongo ifé Rè fún è láìfibò rárá. Ó pinnu láti wá fún è!
Ó ni Olùgbàlà kan tó wa committed sí o. Òun ní òré tó fà mọ́ni tímọ́tímọ́ jù arákùnrin llrè lo — ènì tó ní ìsopò pèlú rè nípa èjè àti ìrírí. Nígbà tí ayé bá dí gbágungbàgun, o lè simi nínú ìmò pé Òun kò lè pa è tì láé. ìwọ kò dá wà rárá..
Bí o se ronú nípa ìdí wíwá Rè ni jù egbèrún ọdún lo sèyín, gbá Olúwa láàyé láti fówó kan okàn rè pèlú ìmólarà lákọ̀tun wíwàníhìn-ín. Bóyá ó ñ tiraka pèlú ìpalárala tó jínlè, àtipe ó máa kọminú pé bóyá bí o má se lè fara da pèlú gbogbo ìrora yen. Jésù—Emmanuel—sún mó è, àtipe Yóò rìn pèlú kojá èyíkéyí àdánwò àti fi ìtùnú fún pèlú okun láàárín èyíkéyí ìjìyà. Jé kí ìtùmó bíbò Rè sínú aiyé mú ìretí tuntun sínú ayé rè kódà ní báyìí.
Isé Sisé: lórí dígí ile bathroom, lo pẹ́ńsùlù gbigbe láti ko àwọn òrò wònyí sílèènì tí a yàn àti ènì tí téwó gba. Ràn ara rè létí láràárọ̀ pé Jésù yàn o àtipe Ó téwó gba o.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ní alẹ́ ìdákẹ́ rọ́rọ́ kan ní ọdún 2000 sẹ́yìn, àwọn angẹli mu ìròyìn ìbí Olùgbàlà wá fún ẹgbẹ́ àwọn daran-daran kan níbi tí wọn ti ń da ẹran wọn. Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ìròyìn náà, àwọn daran-daran wọ̀nyí fi ohun gbogbo sí'lẹ̀ láti wá ìkókó tí ó wà ní ibùjẹ ẹran ní Bẹtilẹhẹmu. Lẹ́yìn gbogbo àwọn ọdún wọ̀nyí, ìpè yìí kò tíì yí padà. Ẹ̀ bá Dr. Charles Stanley rìn bí ó ṣe ń ràn yín l'ọ́wọ́ láti súnmọ́ Olùgbàlà, àti láti mú ọkàn yín le láti wá àyè láti sinmi nínú ìfẹ́ Bàbá ní àkókò yíì.
More