Ìrìn àjò lo si Ìbùje EranÀpẹrẹ
Ìfé Aláìlópin
Ìfé Olórun kò pìn sí ìrírí ìgbàlà; o nawó sí gbọgbo ìgbésí ayé. Nínú ọgbà Édẹ́nì— léyìn tí Ádámù àti Éfà da ẹ̀sẹ̀— Olórun kò pa ìfé Rè fún ẹdá ènìyàn tí láé. O lẹ̀ tí jáwọ́ lọ́rọ̀ m wọn, àmó kò sè bẹẹ. O féràn wọn àti pé O pinnu láti mú wọn padà wá sínú àjọṣe onífé pẹ̀lú ara Rè. Jálè Májẹ̀mú láéláé. A rí Olórun ń nàgà lérálérá nínú ìfé, ni gbogbo àkókò náà tí O ń gbára dì ìtàgé fún bíbọ ìgbàlà Rè.
Jésù Kristi ní ìmúsé ìlérí ojó pípé tí òòrè-ọfẹ ìgbàlà pípé fún ẹdá ènìyàn. Ìbí Rè ní ìwé kúkúrú tí Olúsèdá fi ọwọ́ kọ sí wa, ń pòkìkí ìfé ayérayé Rẹ̀ tó lépa àti gbàlà Jálè gbogbo àkókò. O lẹ̀ tí dúró sí òrun, jìnnà sí àìararo àti àwọn ìnílára tí ayé yìí tó tí túká, àmó O m pé a nílọ̀ ìfé yìí tí Òun nìkan lè pèsè. Bí o ń tí ṣe àjọyọ̀ ìbi Olùgbàlà wa, sàgbéyẹ̀wọ̀ ohun tí o sò it nípa ìfé Rè tó jìnlẹ̀ fún o.
Isé Ṣiṣé: Sápá Láti sèrànwọ́ fún mọ̀lẹ́bí tàbí òré èyí tí o ní láti padà bá ara rẹ̀ rẹ́. D'áríjì nítorí Olórun kókó d'áríjì o.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ní alẹ́ ìdákẹ́ rọ́rọ́ kan ní ọdún 2000 sẹ́yìn, àwọn angẹli mu ìròyìn ìbí Olùgbàlà wá fún ẹgbẹ́ àwọn daran-daran kan níbi tí wọn ti ń da ẹran wọn. Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ìròyìn náà, àwọn daran-daran wọ̀nyí fi ohun gbogbo sí'lẹ̀ láti wá ìkókó tí ó wà ní ibùjẹ ẹran ní Bẹtilẹhẹmu. Lẹ́yìn gbogbo àwọn ọdún wọ̀nyí, ìpè yìí kò tíì yí padà. Ẹ̀ bá Dr. Charles Stanley rìn bí ó ṣe ń ràn yín l'ọ́wọ́ láti súnmọ́ Olùgbàlà, àti láti mú ọkàn yín le láti wá àyè láti sinmi nínú ìfẹ́ Bàbá ní àkókò yíì.
More