Ìrìn àjò lo si Ìbùje EranÀpẹrẹ

Journey To The Manger

Ọjọ́ 25 nínú 70

Jésù ñ Yí Ayé Padà

Ní alé ojó tí a bí Jésù àwọn òlúsó àgùntàn dí elẹ́rìí àkókó Rè. Fójú inú wó bí ìròhìn náà se tànkálẹ̀ kaakiri láti ènìkan sí ènìkan. Bẹ́tílẹ́hẹ́mù kún fún àwọn arìnrìn àjò tó ti rè, àtipe ó má ti sòro láti gbójú fo kàyéfì àti ìmóríyá àwọn òlúsó àgùntàn náà’.

Láti ìbí Rè sí ìgòkè-re-ọ̀run Rè, Jésù sáyípadà ayé gbogbo àwọn tó nírírí Rè. Nítorí ifé Rè sáyípadà ohun tó bá fówó kan, Ó sì sa ipa lórí aiyé wa. Àtipe nípasè àwọn kan lára wa tó tí yípadà nípa ifé Rè, Ó tésíwájú láti fowó kàn àwọn tó sonù pèlú ìhìn rere tí ayé tuntun Rè. Bí àwọn òlúsó àgùntàn àkókó náà tí Kérésìmesì, a jé àwọn òjíṣẹ́ Rè.

Kíní ìtàn rè bí Jésù se yí ayé rè padà? Èbùn ńlá wo ní o lè fúnni tó jù kí o pín ifé Rè pèlú àwọn tó palára tàbí àwọn tó ñ wá gbéregbère kiri?

lónìí, sájọyò ìbí Rè—àti gbogbo ònà Tó tí fi ifé aláìyẹsẹ̀ Rè hàn sí è. Lèyín ìgbà náà lo so fún àwọn elómìrán pé Ò nífèé wọn, náà, pèlú ifé pípé.

Isé Sisé: Sàjọpín ìròhìn rere tí ìdùnnú ńlá! So fún ènìkan nípa Jésù àtipe sa ipa tí Jésù ni lórí ayé rè.

Síra tẹ níbí láti kẹ́kọ̀ọ́ síi nípa sisún mó Bàbá ati mímú ìbáṣepò jínlè sí i pèlú Rè.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 24Ọjọ́ 26

Nípa Ìpèsè yìí

Journey To The Manger

Ní alẹ́ ìdákẹ́ rọ́rọ́ kan ní ọdún 2000 sẹ́yìn, àwọn angẹli mu ìròyìn ìbí Olùgbàlà wá fún ẹgbẹ́ àwọn daran-daran kan níbi tí wọn ti ń da ẹran wọn. Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ìròyìn náà, àwọn daran-daran wọ̀nyí fi ohun gbogbo sí'lẹ̀ láti wá ìkókó tí ó wà ní ibùjẹ ẹran ní Bẹtilẹhẹmu. Lẹ́yìn gbogbo àwọn ọdún wọ̀nyí, ìpè yìí kò tíì yí padà. Ẹ̀ bá Dr. Charles Stanley rìn bí ó ṣe ń ràn yín l'ọ́wọ́ láti súnmọ́ Olùgbàlà, àti láti mú ọkàn yín le láti wá àyè láti sinmi nínú ìfẹ́ Bàbá ní àkókò yíì. 

More

A fé láti dúpé lówó Isé òjísé Touch fún ìpésé ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí, E jòó ṣèbẹ̀wò visit: https://intouch.cc/yv18