Ìrìn àjò lo si Ìbùje EranÀpẹrẹ

Journey To The Manger

Ọjọ́ 8 nínú 70

Èdá Olórun Tó Ñ Yà Ni Lénu

Nígbà Mìíràn ó dà bí pé Olórun kò ni gbó àdúrà wa láé. Bé ní ó se rí fún àwọn ènìyàn Ísírẹ́lì bí wón ñ se retí bí wón sey dúró dé bíbò Mésàyá. Nígbà tí Jésù wá, didé Rè wá Lákòókò kan gélé. Àmó òpò kò mò ìpèsè pàtàkì Olórun nítorí wón dúró dé Mésàyá tó má gbé wón àti orílẹ̀-èdè wón ga—dípò Olúwa funra Rè.

Kristi wá láti pèsè ìgbé ayé yàtọ̀ sí ohunkóhun tí ayé lè pèsè. Ó lè tí wá pèlú agbára àìlópin ti òrun. Dípò, Ó yàn láti wá sáyé ni ìrèlè, gégé bí omo ìkókó tí a bí láàárín àwọn eranko. Síbè ìgbé ayé àìròtẹ́lẹ̀ àti ipò omo ìránsé Rè finhàn sí wa ìjépípé ifé tí kó kù síbì kankan ti Olórun fún aráyé.

Isé Sisé: Nígbà Mìíràn tó bá jẹun nílé àrójẹ, yà agbawó onje rè lénu pèlú owó díè tó làwọ́ ju ìpíndọ́gba owó tón gbá. Tó bá fé èyí, fi ìwé owó níṣìírí ti tara rè sílè.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 7Ọjọ́ 9

Nípa Ìpèsè yìí

Journey To The Manger

Ní alẹ́ ìdákẹ́ rọ́rọ́ kan ní ọdún 2000 sẹ́yìn, àwọn angẹli mu ìròyìn ìbí Olùgbàlà wá fún ẹgbẹ́ àwọn daran-daran kan níbi tí wọn ti ń da ẹran wọn. Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ìròyìn náà, àwọn daran-daran wọ̀nyí fi ohun gbogbo sí'lẹ̀ láti wá ìkókó tí ó wà ní ibùjẹ ẹran ní Bẹtilẹhẹmu. Lẹ́yìn gbogbo àwọn ọdún wọ̀nyí, ìpè yìí kò tíì yí padà. Ẹ̀ bá Dr. Charles Stanley rìn bí ó ṣe ń ràn yín l'ọ́wọ́ láti súnmọ́ Olùgbàlà, àti láti mú ọkàn yín le láti wá àyè láti sinmi nínú ìfẹ́ Bàbá ní àkókò yíì. 

More

A fé láti dúpé lówó Isé òjísé Touch fún ìpésé ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí, E jòó ṣèbẹ̀wò visit: https://intouch.cc/yv18