Ìrìn àjò lo si Ìbùje EranÀpẹrẹ

Journey To The Manger

Ọjọ́ 7 nínú 70

Ojúlówó àjọṣe pèlú Olórun

Isé pàtàkì tí ifé Olórun bèrè kódà sáájú ọgbà Édẹ́nì. Kí a tó se ìpìlẹ̀ ayé àti jálẹ̀ àkókò, Ó tẹ̀síwájú ni gbigbé ìgbésè síhà góńgó kan: ìmúpadàbọ̀sípò ojúlówó ìbáṣepò Rè pèlú ènìyàn.

Kí a tó lé wón kúrò nínú ọgbà Édẹ́nì, a se ìpèsè ìgbẹ́mìíró fún Ádámù àti Éfà tí a se láti inú àwon awo eranko. Isé Olórun yìí—ñ se fifi èmí àwọn eranko yìí se ìrúbo láti se ààbò fún ìtíjú ènìyàn—jé àpẹẹrẹ ìṣáájú fún ebo ojó ìwájú, èyí tó pèsè ìgbàlà òtító àti pípé fún wa.

Jésù wá sáyé fún isé pàtàkì ti ifé. Nípasè ebo ńlá Rè, a tí múwa padàbọ̀sípò sí ojúlówó ipò wa ti ìbáṣepò pèlú Olúsèdá wa.

Isé Sisé: Ñjé o mo ènìkan ti kò ní ìfọ̀kànbalẹ̀ ni ṣọ́ọ̀ṣì? Pè wón wá láti se àpéjọpọ̀ ìsìn tó tè lé e pèlú è kí wón má nímólarà didá nìkan wà.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 6Ọjọ́ 8

Nípa Ìpèsè yìí

Journey To The Manger

Ní alẹ́ ìdákẹ́ rọ́rọ́ kan ní ọdún 2000 sẹ́yìn, àwọn angẹli mu ìròyìn ìbí Olùgbàlà wá fún ẹgbẹ́ àwọn daran-daran kan níbi tí wọn ti ń da ẹran wọn. Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ìròyìn náà, àwọn daran-daran wọ̀nyí fi ohun gbogbo sí'lẹ̀ láti wá ìkókó tí ó wà ní ibùjẹ ẹran ní Bẹtilẹhẹmu. Lẹ́yìn gbogbo àwọn ọdún wọ̀nyí, ìpè yìí kò tíì yí padà. Ẹ̀ bá Dr. Charles Stanley rìn bí ó ṣe ń ràn yín l'ọ́wọ́ láti súnmọ́ Olùgbàlà, àti láti mú ọkàn yín le láti wá àyè láti sinmi nínú ìfẹ́ Bàbá ní àkókò yíì. 

More

A fé láti dúpé lówó Isé òjísé Touch fún ìpésé ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí, E jòó ṣèbẹ̀wò visit: https://intouch.cc/yv18