Ìrìn àjò lo si Ìbùje EranÀpẹrẹ

Journey To The Manger

Ọjọ́ 6 nínú 70

O Yahànhàn fún Wa

Jésù ní Olórun kí ayé tó bèrè—Òun ní òrò tó jé pé nípasẹ ní a dà ohun gbogbo. O wà nínú ọgbà Édẹ́nì pèlú Ádámù àti Éfà Ọkàn Rè gbà ọgbé inú àkókó tí ìwà ipá tí ẹ̀sẹ̀ tó fò àjọṣe tímọ́tímọ́ láàrín Òun àti isèdá Rè

Jálè gbogbo àkókò, O wo àwọn ènìyàn Rè ń tiraka. O gbà wón là àti darí wọn gba inú aginjù. O hànhàn fún won láti fé Òun nìkan, síbẹ̀ àwọn ọkàn wọn jìnnà sí Í bí wọn ń ṣe, àwọn òrìṣà aláìníláárí tí ènìyàn dá.

Ronú nípa bí Jésù ṣe tí má wo àti gbàdúrà láti enú ìlèkùn òrun ọdún léyìn odún. Nígbà tí ẹ̀kúnréré ìgbà bá ti wá, sàgbéyẹ̀wọ̀ ìdùnnú Rè ní bíbọ wá sódò wa gégé bí Olùgbàlà wa.

Isé Ṣiṣé: Pè àwọn aládùúgbò kan sódò rẹ̀ fún ṣokoléètì àti fún ìkẹ́gbẹ́pọ̀.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 5Ọjọ́ 7

Nípa Ìpèsè yìí

Journey To The Manger

Ní alẹ́ ìdákẹ́ rọ́rọ́ kan ní ọdún 2000 sẹ́yìn, àwọn angẹli mu ìròyìn ìbí Olùgbàlà wá fún ẹgbẹ́ àwọn daran-daran kan níbi tí wọn ti ń da ẹran wọn. Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ìròyìn náà, àwọn daran-daran wọ̀nyí fi ohun gbogbo sí'lẹ̀ láti wá ìkókó tí ó wà ní ibùjẹ ẹran ní Bẹtilẹhẹmu. Lẹ́yìn gbogbo àwọn ọdún wọ̀nyí, ìpè yìí kò tíì yí padà. Ẹ̀ bá Dr. Charles Stanley rìn bí ó ṣe ń ràn yín l'ọ́wọ́ láti súnmọ́ Olùgbàlà, àti láti mú ọkàn yín le láti wá àyè láti sinmi nínú ìfẹ́ Bàbá ní àkókò yíì. 

More

A fé láti dúpé lówó Isé òjísé Touch fún ìpésé ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí, E jòó ṣèbẹ̀wò visit: https://intouch.cc/yv18