Ìrìn àjò lo si Ìbùje EranÀpẹrẹ

Journey To The Manger

Ọjọ́ 4 nínú 70

Ìmólè Borí

Ìbí Jésù wá nígbà tí òkùnkùn tèmí bò ìlú. Àwon ènìyàn Ísráẹ́lì gbàgbé àwọn ònà Olúwa. Téńpìlì ti dí ibi ojà títà; wón rú ebo nítorí o jé ojúse àti àsà dípò fún óùngbẹ láti se ìjosìn Olórun. Àti retí bíbò Mèsáyà saábà máa ñ jé ìfé-okàn ayé fún ìgbàlà ológun àti ìpparun àwọn aninilára Róòmù.

Àmó Jésù wá fún ète kan tó ré kọjá ààlà pátápátá àwọn ònà ìronú wònyí. Lótító, Ó wá láti pa àwọn isé òtá run—èyí tó jé, àwọn òtá okàn wa. Ó fidí ìjoba Rè múlè lórí ayé nípa fifi ẹ̀mí rẹ̀ lélẹ̀ gégé bí ẹbọ ètùtù tí ifé àti ìdáríjì—kí gbogbo ọkùnrin àti obìnrin lè ní ìyé lópọ̀ yanturu tòótó.

Isé Sisé: Tàn ìmólè sójó enìkan—gbá àwon òrè kan mú ke lo si Orin Kérésì. Tí àdúgbò rè kì i se ohun tó fé, gbígbìyànjú ìrànlówó nínú ẹgbẹ́ àwùjọ kan.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 3Ọjọ́ 5

Nípa Ìpèsè yìí

Journey To The Manger

Ní alẹ́ ìdákẹ́ rọ́rọ́ kan ní ọdún 2000 sẹ́yìn, àwọn angẹli mu ìròyìn ìbí Olùgbàlà wá fún ẹgbẹ́ àwọn daran-daran kan níbi tí wọn ti ń da ẹran wọn. Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ìròyìn náà, àwọn daran-daran wọ̀nyí fi ohun gbogbo sí'lẹ̀ láti wá ìkókó tí ó wà ní ibùjẹ ẹran ní Bẹtilẹhẹmu. Lẹ́yìn gbogbo àwọn ọdún wọ̀nyí, ìpè yìí kò tíì yí padà. Ẹ̀ bá Dr. Charles Stanley rìn bí ó ṣe ń ràn yín l'ọ́wọ́ láti súnmọ́ Olùgbàlà, àti láti mú ọkàn yín le láti wá àyè láti sinmi nínú ìfẹ́ Bàbá ní àkókò yíì. 

More

A fé láti dúpé lówó Isé òjísé Touch fún ìpésé ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí, E jòó ṣèbẹ̀wò visit: https://intouch.cc/yv18