Ìrìn àjò lo si Ìbùje EranÀpẹrẹ

Journey To The Manger

Ọjọ́ 2 nínú 70

Jésù Ni Ìlérí Olórun

Wòlíì lèyín wòlíì sotélè bíbò Mésàyá. Òpò àṣà ìbílẹ̀ àti àjọ̀dún tí Ísírẹ́lì jé òjìji ohun tó má wá pèlú ifarahàn Rè. Síbè bí òrúndún lèyín òrúndún se kọjá lo, ayé dà bí pé ó ñ lo bí se sábà máa rí láìsi ìdíwọ́ àtòrunwá tí a selérí. Ñjé àwọn òrò Olórun sí àwọn ènìyàn Rè jé ìlérí òfifolasán? Se gbogbo àwọn wòlíì náà lòdì? Se ènìyàn yàn kádàrá láti gbé ìgbé ayé sekésekè èsè àti ìgbèkùn?

Nígbà náà, ní ojó tó bèrè bí gbogbo ojó mìíràn, tó hànhàn fún ìdíwọ́ àtòrunwá wá ìrísí omo ìkókó tó máa sàyípadà kádàrá aráyé. Fún gbogbo àwọn tó n tí dúró dé E, Jésù wá kélékélé àti láìsi afẹfẹyẹ̀yẹ̀. Àmó ni ojó ìbí Rè ayé yípadà gidigidi. Kó sí ohun tó máa dá bíi ti tẹ́lẹ̀ mọ́ láé..

Isé Sisé: Ronú lórí èrí rè. Ṣàkọsílẹ̀ àwọn ònà pàtó tí ayé rè fi yípadà nígbà tí o gbá Jésù. Pín èrí rè pèlú àwọn elegbé onigbágbó rè láti ta wón jí sí ìgbàgbó ńlá.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 1Ọjọ́ 3

Nípa Ìpèsè yìí

Journey To The Manger

Ní alẹ́ ìdákẹ́ rọ́rọ́ kan ní ọdún 2000 sẹ́yìn, àwọn angẹli mu ìròyìn ìbí Olùgbàlà wá fún ẹgbẹ́ àwọn daran-daran kan níbi tí wọn ti ń da ẹran wọn. Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ìròyìn náà, àwọn daran-daran wọ̀nyí fi ohun gbogbo sí'lẹ̀ láti wá ìkókó tí ó wà ní ibùjẹ ẹran ní Bẹtilẹhẹmu. Lẹ́yìn gbogbo àwọn ọdún wọ̀nyí, ìpè yìí kò tíì yí padà. Ẹ̀ bá Dr. Charles Stanley rìn bí ó ṣe ń ràn yín l'ọ́wọ́ láti súnmọ́ Olùgbàlà, àti láti mú ọkàn yín le láti wá àyè láti sinmi nínú ìfẹ́ Bàbá ní àkókò yíì. 

More

A fé láti dúpé lówó Isé òjísé Touch fún ìpésé ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí, E jòó ṣèbẹ̀wò visit: https://intouch.cc/yv18