Àlàyé nípa Ètò Bíbélì

Nígbàtí Ìgbàgbọ́ Bá Kùnà: Ọjọ́ Mẹ́wàá Nípa Wíwá Ọlọ́run Nínú Òjìji IyèméjìÀpẹrẹ

When Faith Fails: 10 Days Of Finding God In The Shadow Of Doubt

Ọjọ́ 4 nínú 10

p> Kàyéfì ló jẹ́ bóyá a kò tí bẹ̀rẹ̀ sí fí ojú míràn wó Bíbélì lọ́nà tí kò tọ́. Bóyá a tí ní ìfẹ́ àfẹ́jù sí àwọn àkọsílẹ̀ átijọ́ bí ó ṣe yanjú àwọn ìbéèrè ìtàn, àṣà, ìmọ̀-ìjìnlẹ̀, àti ìhùwàsí tí ó fí jẹ́ wípé ó mú iyèméjì wà. Ṣùgbọ́n bí ó bá jẹ pé irú àgbékalẹ̀ rẹ kò bá ní ọgbọ́n tí ó dánilójú, ṣùgbọ́n èyí tí ó lè ṣe amọ̀nà wá sí ìbásepọ̀ pẹ̀lú Ọlọ́run.

Bóyà a nílò láti fí ojú àtijọ́ wò Bíbélì pẹ̀lú (Báwo ní eléyìí ṣe jẹ ọgbọ́n?) tàbí fí ojú òde òní wò (Báwo ní eléyìí ṣe bá wà sọ̀rọ̀?) Á sí tún lè gbà á bí ó tí ṣe rí, tàbí ohun tí ó jẹ, gẹ́gẹ́bí ohun tí ó lárinrin, tí ó jẹ èémọ̀, ohun tí ó ṣòro, tí ó jẹ ohun ìpèníjà, ìwúnilórí, tí ó fani móra, tàbí ohun tí ó jẹ ìwé ìdàrúdàpọ̀ láti ojú ìwé de ojú ìwé àti ìtàn de ìtàn títí ó fí yọrí sí ọ̀dọ̀ ẹniti á pé ní Jésù.

Bí eléyìí bá sì jásí òtítọ́, nígbà náà, irú ìbásepọ̀ èyíkéyìí tí í bàá jẹ́, ó gbà ní lásìkò.

Á nílò ìfaradà láti ní àròjínlẹ̀ tí ó tayọ ohun àtijọ́ kí a sì gbẹ ilẹ̀ kọjá ibi líle láti fí ojú òtítọ́ lédè.

Àti pé à nílò ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwà ìrèlẹ̀ láti mú àtúnṣe bá ìrònú wá nígbàtí ó bá sẹlẹ bẹ́ẹ̀.

Ní èyíkéyìí ọ̀nà tí í bàá jẹ́, mó ní àlàáfíà láti mọ pé àwọn onkowe náà ní ó tún n ṣiyèméjì lórí wọn. Àwọn náà tiraka pẹ̀lú. Ṣùgbọ́n wọ́n bàa rìn lọ ní ọ̀nà Emmausi, nítorí pé wọ́n gbagbọ pé ní ìgbẹ̀yìn-gbẹ́yín gbogbo nkan yíò wà dáradára. Nwọn ní ìrètí pé lọ́jọ́ kán àti lọ́nà kán wọ́n yíò rí Olùgbàlà wọn

Àti pé ìyẹn ní ohun tí ó jẹ kì Bíbélì má ṣe jẹ ohun tí á ní láti gbẹ́kẹ̀lé nikan bí kò ṣe ohun tí ó mú ìgbé ayé wa rọrùn sì.

Ọjọ́ 3Ọjọ́ 5

Nípa Ìpèsè yìí

When Faith Fails: 10 Days Of Finding God In The Shadow Of Doubt

Ìlàkàkà pẹ̀lú ìgbàgbọ́ àti iyèméjì jẹ́ ohun tí ó lè jẹ́kí ènìyàn fẹ́ dáwà tàbí kí ó ya ara rẹ̀ sọ́tọ̀ kúrò lọ́dọ̀ àwọn ẹlòmíràn. Àwọn kàn ńdá jìyà láìjẹ́ kí enìkankan mọ̀, àwọn míràn kọ ìgbàgbọ́ sílẹ̀ lápapọ̀, wọ́n rò pé...

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ HarperCollins fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, Jọ̀wọ́ lọsí: http://bit.ly/2Pn4Z0a

YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa