Nígbàtí Ìgbàgbọ́ Bá Kùnà: Ọjọ́ Mẹ́wàá Nípa Wíwá Ọlọ́run Nínú Òjìji IyèméjìÀpẹrẹ
Ti ilè ba jé ìgbé ayé ìgbàgbọ́, ìyèméjì ní ònà tí a gbódò rìn tí a máa fi dé bè. Lóòótọ́, àwọn ìpèníjá máa wá lórí ìpà ọnà náà: àwọnìdẹkùn, idáníkànwà, ìbínú, ìbẹrù, ìbéèrè. A mú ọrọ yìí ìbéèrè wá láti. inú èdè Latin quaerere, ibi kan náà tí a ti fa ọrọ gẹ̀ẹ́sì náà quest yọ. Wíwànǹkan, bí àwon ìrìn àjò onígboyà mìíràn, a máa rìn pẹ̀lú ìdíwo. Gbogbo ipè lo ní ohun tómáa náni. Àwọn òkè gíga lọ níra láti gun. Àfonífojì je aronilára láti ifáradà. Fún òpò ènìyàn, béèni bí lílo si ilè se dá bí. Àwọn mìíràn tí Mo mọ̀ (tí mo si jowú won) ní àwọn àkókò tó rọrùn. Ìrìn àjò láti lọ sílé jé òpópónà olójú mérin; bosí inú okò ayọkẹlẹ rè kíá ọ tí délé. Àwọn mìíràn, bi èmi, wà lórí ojú ònà títẹ́jú.
Lédè kan ṣá, wíwà nǹkan
Lédè kan ṣá, a kò dá wà nìkan. . . .
Nǹkan dojú ru a si dá nìkan wà , tí a ń nà nínú ìdààmú bi a ń ṣe ń yẹ àwọn pàǹtírí náà bí a ń ṣe wá ète. A ko ìwé pẹlẹbẹ méjì lé wa lówó. Oòkan ni kò sí ìtùmò ní ayé. Àsìse ní gbogbo e. Àwọn ohun kánkan máa ń kan ṣẹlẹ̀. Atípe lóro kan sa, àsìse n'iwọ náà.
Àmó Jésù fún wa ni ìwé mìíràn. Ọ sọ pé ayé ní ìtumò. Àti gbogbo ohun nípa ẹnì ti o jé, èémí tó ń lọ káàkiri inú èdófóró e , ọkàn ẹ tó ń lu kìkì ní àyà ẹ, ẹkùn e, àwọn èrú e, àti àwọn ìran e, ọ̀ràn e. Ọ ṣèlérí pé ìdájọ́-òdodo máa jọba àánú, máa ṣógo, a máa tún ohun tó báje kô ; O si pé wa láti dárapò pèlú Òun ní ònà tó dára jù ti a mò.
Àwọn mìíràn so wí pé ayé kò jú méríìrí lo. Àtipe , ta lómò, bóyá wón rí sò. Bóyá à wà lára àwon asiwèrè, to lòdì sí ìrònútí kò wõ lójú. Àmọ́ sa ọ kàkà béè ma gbé ìgbé ayé mi n'irèti, wíwá Ọlórun to rẹwà, ju nínú ìrora àti ahòro ayé àìdá bi olórun.
Mo gbàgbọ́ pé púpò yìí wá nípa ìwàláàyè ìyàtò to fojualáìlàánú.
Mo gbàgbọ́ nínú Ọlọ́run tó ṣèdá wa, féràn wa, fi èmí ará é lẹ́lè fún wa , Ọ ń sí sún wá sọ́dọ̀ Rè láìdáwódúró, aláìiseyípadà, tìfétìfé, sí ara rè.
Mo gbàgbọ́ pé ìdí wà láyé yìí.
Mo gbàgbó pé ikú kò ní ìgbéyin òrò .
Mo gbàgbọ́ nínú òtító gíga ju lọ atipe . . . O kún fún ìyé, ẹwà, aqo, àti ìjìnlè.
Mo gbàgbọ́ pé ìyèméjì jé ará ènìyàn. O mú wá dúró gbọn-in, páwa lára, nígbà náà—àmó tí a bá gbà láàyè—o máa yọrí sí ìgbàgbọ́ tó jinlẹ̀.
Mo gbàgbọ́ pé tí oòrùn bá sọ́kùnkùn, ọ máa pàdà Ìmúÿókùnkùn yìí máa kọjá. Ayé lè dàbí pé ọ yàtò. Béè náà ni àwa.
Mo sí gbàgbó pé òpò mbè nípa wa jù bẹ́ẹ̀ lọ.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ìlàkàkà pẹ̀lú ìgbàgbọ́ àti iyèméjì jẹ́ ohun tí ó lè jẹ́kí ènìyàn fẹ́ dáwà tàbí kí ó ya ara rẹ̀ sọ́tọ̀ kúrò lọ́dọ̀ àwọn ẹlòmíràn. Àwọn kàn ńdá jìyà láìjẹ́ kí enìkankan mọ̀, àwọn míràn kọ ìgbàgbọ́ sílẹ̀ lápapọ̀, wọ́n rò pé iyèméjì kò ní ìbámu pẹ̀lú ìgbàgbọ́. Dominic Done gbàgbọ́ wípé èyí jẹ́ àsìse àti oun tí ó bani lọ́kàn jẹ́. Ó lo Ìwé mímọ́ àti ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ láti jiyàn wípé bíbèèrè nípa ìgbàgbọ́ bójúmu àti wípé ó sábà máa ńjẹ́ ọ̀nà síhà ìgbàgbọ́ tí ó lọ́rọ̀ àti tí ó lárinrin. Yẹ ìgbàgbọ́ àti iyèméjì wò nínú ètò ọlọ́jọ́ mẹ́wàá yìí.
More