Àlàyé nípa Ètò Bíbélì
Nígbàtí Ìgbàgbọ́ Bá Kùnà: Ọjọ́ Mẹ́wàá Nípa Wíwá Ọlọ́run Nínú Òjìji IyèméjìÀpẹrẹ
![When Faith Fails: 10 Days Of Finding God In The Shadow Of Doubt](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F13765%2F1280x720.jpg&w=3840&q=75)
Nínú ìwé Ẹ́kísódù, nígbà tí Olórun sò fún Mósè pé kí o bò bàtà ẹsè e, ìdí nì wípé o ń dúró lórí ilè mímọ́. Èyí máa tí yàa lẹ́nu! O mò apá àsálè yẹn dáadáa. O tí rìn lórí e fún ogójì ọdun gẹ́gẹ́ bí olùṣọ́àgùntàn. Fún Mósè, ibí tó tí ṣíṣe ní. Nínú ọkàn rè ilé náà kan jé ilè ìdọ̀tí ̣ẹlerúku to wọ́pọ̀, ilè tí àwọn àgùntàn tí-tè mọ́lẹ̀. Àmọ́ Olórun mò pé ilè mímó ni.
Wi pé ilẹ̀ ti o wá báyìí kún fún Ìjèmímó? Tí òjìji Olórun bá gbilè kan nínú kùlèkùlè ayé e? To bá jé pé afẹ́fẹ́ tí o wà láyìíká e báyìí o ni ohùn E?
Olórun ṣòrò. O kàn lè má jé ní ònà tí o ń retí.
• O ń sọ̀rọ̀ nípasẹ̀ àwọn ẹlòmíràn. Kódà àwọn tón bí e ninú.
• O ń ṣòrò nípasẹ̀ àwọn isé ònà: àwọn ìwétódára, ohùn orin, ewì, àwọn orin, àti àwọrán.
• O lè ṣòrò látojú àlá. . . .
• O ń sọ̀rọ̀ nípasẹ̀ ìṣẹ̀dá, bi a ń ṣe mí èémí èwà ohun tí Ó ṣèdá.
•O sọ̀rọ̀ nípasẹ̀ ẹ̀rí ọkàn àti ìmọ̀lára pé nǹkan kan wromg . (Nígbà mìíràn kìí se pé Ọlọ́run dáké àmó ohùn ẹsè tón di etí ẹni. Èsè fe jé ohùn tó lọ sókè ju nínú ayé wa. Má sé fàyè gbà.)
•O ń sòrò nípasẹ̀ ìrora wa.
• O ń sọ̀rọ̀ nípasẹ̀ àdánù wa.
• Kódà O tún sọ̀rọ̀ nínú ìyèméjì wa.
Ti Olórun ba mbè, kò sì nǹkan kan bí ilè lásán. O má jé mímọ. Lásìkò yìí, lówó lówó báyìí, ibikíbi tío bá wa, o jé mímó. Olórun pè e láti bò bàtà e kí o si ìka esè in kí o bẹ̀re si ni yín Olúwa.
O wà nibi.
>Ìtèka Olórun mbè káàkiri ayé e.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
![When Faith Fails: 10 Days Of Finding God In The Shadow Of Doubt](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F13765%2F1280x720.jpg&w=3840&q=75)
Ìlàkàkà pẹ̀lú ìgbàgbọ́ àti iyèméjì jẹ́ ohun tí ó lè jẹ́kí ènìyàn fẹ́ dáwà tàbí kí ó ya ara rẹ̀ sọ́tọ̀ kúrò lọ́dọ̀ àwọn ẹlòmíràn. Àwọn kàn ńdá jìyà láìjẹ́ kí enìkankan mọ̀, àwọn míràn kọ ìgbàgbọ́ sílẹ̀ lápapọ̀, wọ́n rò pé...
More