Àlàyé nípa Ètò Bíbélì

Nígbàtí Ìgbàgbọ́ Bá Kùnà: Ọjọ́ Mẹ́wàá Nípa Wíwá Ọlọ́run Nínú Òjìji IyèméjìÀpẹrẹ

When Faith Fails: 10 Days Of Finding God In The Shadow Of Doubt

Ọjọ́ 9 nínú 10

Ohun tó gbìn sínú ọkàn Olórun , ni ki ìjọ je gbé bí ebí kan. Sóòsì níbi tí a tin jíjàkadi, ṣe ìyàlẹ́nu, ṣe ìjọsìn, àti ṣiyèméjì papò. Sóòsì ni ibi tí a máa wá ìwòsàn fún àfókù ayé àtijó wọn , ìtẹ́wọ́gbà, ai óòré òfẹ́. Ṣóòsì nibi tí àwọn ènìyàn tí wọn ní ìpalára tí máa mò pé àwọn kò dá nìkan wa. Èyí ní ìran Olórun nígbà tí O kókó dà Èmí E sórí ìjọ ní ìṣe àwọn àpọ́sítélì orí 2. Èyí ni ìran Olórun fún ẹ.

Òtító ni pé òpò ìjọ kò ti bẹ̀rẹ̀ si ni mú ìran yìí ṣè. Òtító ni pé òpò nǹkan lọ ní láti yí padà, àmọ́ ìwọ lè jẹ́ ìyípadà náà.

Ìwọ ni ìjọ náà.

Sóòsì kìí se ilé to a kö àmó àwùjọ àwọn ènìyàn tón pirsue ònà Jésù papò. Èyí túmọ̀ si gbi gbàrà lè gbogbo ohun tó ba se dáradára, tó rẹwà, àti to se rúdurùdu nípa ìgbàgbọ́ wa—àti ara wa. O túmọ̀ jíjàkadi papò nínú ìyèméjì wa.

Ní Mátíù 26, wákàtí die kí o tó kú, Jésù jókòó sídìí tábìlì pèlú àwọn òré re. Wón Kọ́rin. Wón gbàdúrà. O si ge ìṣù búrẹ́dì kan; O mú ife wáìnì O pín láàrín wọn. O wípé, “Èyí ni ará mi ; Èyí ni ẹ̀jẹ̀ mi. E jé kí ẹ sì mú ú ní ìrántí mi .” láàrín àwon to jókòó sídìí tábìlì, ní oríṣiríṣi ègbé ènìyàn pèlú àwọn ọ̀ràn to gidi gan, ìyèméjì, àbúkú, àti ìlàkàkà pèlú ìgbàgbọ́ won.

Àmó Jésù tẹ́wọ́ gbà wón tówotésè. O pín ará e tí a pa lára pèlú pèlú wón. O pèsè àyè fún wọn lórí tábìlì.

Níbo ni ìjùmòsòròpò fún o? Tani àwọn tó jókòó sídìí tábìlì ẹ ti o fọkàn tán pèlú àṣírí ayé e? Ni ònà wo ni ó lè gbà sọ fún wón nípa ìpalára ẹ?

O kò ní láti dánì fara dà ìyèméjì. . . .

Ti o mba jíjàkadi pèlú ìyèméjì, ó ní láti wà nínú àwùjọ kan.

Èyíkìíse fúnọ lásán; O jé nítorí àwọn mìíràn. Kódà bí ó bá tíè if you’re not tiraka pèlú ìyèméjì, ó wà fún àwọn tó mbè nítòsí e. Won nílò e. They ache for your fún àdúrà e, tẹ́tí etí ìgbọ́, àti àwọn ọ̀rọ̀ ìṣírí. Gbólóhùn òròìṣírí túmọ̀ sí “látifúnniní ìgbòyà.” O ní àgbàrá láti pín ìgbòyà pèlú ẹni tón fi ìgbàgbọ́ ẹ ráre. Oòkan lára òrò tó lágbára jù ti o lè so fún ẹni tó ń ṣiyèméjì ni, “Máa féràn ẹ bí ó ń ṣe là èyí kọjá.” Wọn nílò e. Won nílò wíwàníhìn-ín iwájú Rẹ. Wón nílò òkun e. Wón sì nílò ogbè e náà. 

Contextrequest   day_9
Ọjọ́ 8Ọjọ́ 10

Nípa Ìpèsè yìí

When Faith Fails: 10 Days Of Finding God In The Shadow Of Doubt

Ìlàkàkà pẹ̀lú ìgbàgbọ́ àti iyèméjì jẹ́ ohun tí ó lè jẹ́kí ènìyàn fẹ́ dáwà tàbí kí ó ya ara rẹ̀ sọ́tọ̀ kúrò lọ́dọ̀ àwọn ẹlòmíràn. Àwọn kàn ńdá jìyà láìjẹ́ kí enìkankan mọ̀, àwọn míràn kọ ìgbàgbọ́ sílẹ̀ lápapọ̀, wọ́n rò pé...

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ HarperCollins fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, Jọ̀wọ́ lọsí: http://bit.ly/2Pn4Z0a

YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa