Àlàyé nípa Ètò Bíbélì

Nígbàtí Ìgbàgbọ́ Bá Kùnà: Ọjọ́ Mẹ́wàá Nípa Wíwá Ọlọ́run Nínú Òjìji IyèméjìÀpẹrẹ

When Faith Fails: 10 Days Of Finding God In The Shadow Of Doubt

Ọjọ́ 5 nínú 10

Ọlọrun kìí ṣe Ọlọrun àlàfo. Òun ní Ọlọrun ohun gbogbo tí ó dá. Ohun tí á mọàtièyí tí á kò mọ. Iṣẹ ọwọ Rẹ̀ ní gbogbo wọn iṣe. Kọ ohun gbogbo tí ó mọ silẹ nípa ìmọ ijinlẹ kí ó sí fí àmì ìbéèrè síwájú awọn ti kò ye ọ to. Lẹhinna fà ìlà kan yípo ara rẹ. Ọlọrun nìyẹn. Àgbáyé jẹ ohun tí ó díjú, tí ó sí jẹ iyalẹnu, ó sì kún fún àdìtú nitoripe bí ó ṣe ṣe àgbékalẹ̀ rẹ nìyẹn. Lẹhinna, ó gbé lé wá lọwọ.

Tìrẹ̀ ní gbogbo nkán

Ọlọrun wà láàrin, ni àyíká, loke, labẹ, Ó si ju ìmọ̀-ìjìnlẹ̀ lọ. Àwárí ẹ̀kọ́ ìjìnlẹ̀ kò ṣe àtakò pé Ọlọrun kòsí bí ẹ̀rọ aláàgbéká iPhone ṣe nṣiṣẹ takò ipilẹṣẹ Tim Cook...........................

Eléyi ṣe pàtàkì. Ìmọ ìjìnlẹ̀ kò gbé Ọlọrun sí ẹgbẹ kan. Ó kan fí hàn wá bí ó ṣe ńṣọlá nínú ìsẹ̀dá àti ẹwà Rẹ.

Ṣugbọn bí ó bá dàbí pé ìforígbárí tí ó hàn kedere bá wá láàrín ọrọ Ọlọrun àti aiyé tí ó gbé kalẹ nko?

Wo, kí ó sí sunmọ dada. Ṣe ìwádí rẹ diẹ ṣí. Tọ̀pinpin rẹ. Béèrè ìbéèrè. Ṣí ọkàn rẹ paya sí ìmọràn pé àtúnyẹwò rẹ nípa iwe mimọ ( tàbí ẹkọ ijinlẹ) jẹ àṣìṣe. Má ṣe fí ìgbàgbọ rẹ silẹ. Má ṣe fí ohun tí ó nifẹ sí julọ silẹ fún ohun tí iwọ kò mọ̀ nkankan nípa rẹ. Rọ̀ mọ ohun tí o jẹ ìyanu tí á kò mọ. Joko ní ẹdọfu. Wá ní pípé pẹlu ohun ijinlẹ.

Nítorípé, tani mọ, ohun ijinlẹ náà lè yanjú ní ọjọ kan, ati pe iwọ yíò s'awari, bóyá kò sí ìforígbárí lẹhin gbogbo rẹ.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 4Ọjọ́ 6

Nípa Ìpèsè yìí

When Faith Fails: 10 Days Of Finding God In The Shadow Of Doubt

Ìlàkàkà pẹ̀lú ìgbàgbọ́ àti iyèméjì jẹ́ ohun tí ó lè jẹ́kí ènìyàn fẹ́ dáwà tàbí kí ó ya ara rẹ̀ sọ́tọ̀ kúrò lọ́dọ̀ àwọn ẹlòmíràn. Àwọn kàn ńdá jìyà láìjẹ́ kí enìkankan mọ̀, àwọn míràn kọ ìgbàgbọ́ sílẹ̀ lápapọ̀, wọ́n rò pé...

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ HarperCollins fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, Jọ̀wọ́ lọsí: http://bit.ly/2Pn4Z0a

YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa