Wiwo Bibeli ti Aisiki

Wiwo Bibeli ti Aisiki

Ọjọ́ 5

Lẹ́yìn ikú Mósè, Ọlọ́run fún Jóṣúà ní àwòkọ́ṣe kan fún jíjẹ́ aásìkí àti àṣeyọrí rere. Nínú ìfọkànsìn ti ọ̀sẹ̀ yìí, a óò gbé àdàkọ yìí yẹ̀wò fínnífínní, ní ṣíṣàyẹ̀wò bí ó ṣe tan mọ́ onígbàgbọ́ òde òní, kí a sì gbára lé Ọlọ́run fún ìjìnlẹ̀ òye sí àwọn òtítọ́ tí ó wà nínú ìmọ̀ràn náà.

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Joshua Sunday Bassey fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/jsbassey

Nípa Akéde