Ifẹ ti o tayọÀpẹrẹ
![Ifẹ ti o tayọ](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F49346%2F1280x720.jpg&w=3840&q=75)
Ijinle Ife Kristi
Ijinlẹ ìfẹ Ọlọrun sí wá jé òún ti akole fi ọkan bikòṣe kíá gbàá gbọ. Oye wa nipa Ọlọrun jẹ ohun to kúrú beni ìfẹ Rẹ ná sugbon bi abaṣe sunmọ lati bá rin ọpọ ìjìnlẹ̀ ìfẹ rẹ ni yíò ma fihan ọ. Eleyi yíò ma ràn ẹ́ lọ́wọ́ lati ma dàgbà ní ìpele ìmọ kan sí òmíràn.
kó ṣeé ṣe láti mọ ijinlẹ ìfẹ Ọlọrun lẹẹkan naa. Ti o bá tákú dìgbà ti o bá ni ẹkúnrẹrẹ́ oyè Ọlọrun kíá to gbáà gbọ ofo ni yíò jasi. Bíbélì wípé "Ọlọrun fẹ arayé to bẹẹ ofi Ọmọ bibii Rẹ kan ṣoṣo fún ni, pé ẹnikẹni to ba gbagbọ́..." Ìfẹ Ọlọrun àwámárìídìí ni ṣugbọn níní ìrírí na san julọ.
Wíwá sínú imọ ìfẹ Ọlọrun sí ọ, jẹ ìmọ tó dára jùlọ fún ọ ati didagba nínú oyè Ọlọrun ati òhún gbogbo tó sè fún ọ nínú Kristi. Ìmọ eyii ni anfaani àìnípẹkun fún ọ jù awọn imọ miran lọ botiwu kì wón lọla to.
Siwaju kika: Ephesians 3:17-19, John 3:16-19
Adura: OLUWA, mó gbagbo nínú ìfẹ Rẹ sí mi, ati òhún gbogbo tó ṣe fún mí nitori ìfẹ tóó ni simi.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
![Ifẹ ti o tayọ](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F49346%2F1280x720.jpg&w=3840&q=75)
Ọkàn nínú awọn ọrọ ti an ṣilo julọ ni "Ìfẹ". An tọka sí ní tó fí aimọkan wa hàn. A un fi ìwà inú, ìbálòpọ̀ ati ṣiṣe ifihan ìfẹ dipo rẹ; eleyii tí àwon Olorin, Eléré ati akowe ìfẹ fín ta ọjà wọn. Sugbọn, Ọlọrun (nínú ìṣẹ̀dá ati ìwà) ni ife, àyàfi tia ba ri ifẹ gẹgẹbi Irisi Bibeli a' ṣi jina sí ririn nínú ìfẹ.
More
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL