Ifẹ ti o tayọÀpẹrẹ
Àwọn Ẹ̀bùn Ẹ̀mí Kò Jẹ́ Rọ́pò fún Ìfẹ́
Bíbélì ṣe akojọ òsì rọ wa láti ṣàwarí awọn ẹbun Ẹ̀mi Mimo torí wọn ṣe iransẹ fún ìjọ wa àti arà kristi.
Síbẹ, ipá wọn kólé ni imusẹ láì sí ìfẹ, eleyii fi pàtàkì ipò ipinle ti ifẹ wa gẹgẹbi òún tíó ṣe kókó yatọ fún ìjọ, sugbọn fún ìdílé ati awujọ wa. Iferan ará wa bi Ọlọrun ṣe ni ife wa yíò ṣe aiye yìí ni ibi ifarada fún ará wa, tíó ní Mu ogún dání, ti a olè fi ifọkanbalẹ gbè.
Ni itọkasi aarin gbungbun ẹkọ yíi, Igbani niyanju náa ni pe, ló ẹbun ẹ̀mi àti ẹbun ti ará tóo ni nínú ìfẹ, ìfẹ rẹ yóò ni ipa tíó dúró láéláé, yíó mọ afárá tíó mu awọn wá sọdọ Kristi lati mú kí ẹbun ẹ̀mi rẹ̀ ni imuṣẹ to pè.
Yíò jẹ ikuna lati ṣe agbéléwọn iṣodódo rẹ nipa ti émi lórí ẹbun Ẹmi Mimo rẹ. Iwọ ojẹ aṣojú to dára fún Ọlọrun nipa rírìn nínú ìfẹ jú gbogbo ona miran lọ.
Siwaju kika: 1 Corinthians 12:1-11, Ephesians 4:11-13,
Adura: OLÚWA rán mi lọwọ láti ṣe abojuto tóyẹ lórí bi mo tinrin nínú ìfẹ.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ọkàn nínú awọn ọrọ ti an ṣilo julọ ni "Ìfẹ". An tọka sí ní tó fí aimọkan wa hàn. A un fi ìwà inú, ìbálòpọ̀ ati ṣiṣe ifihan ìfẹ dipo rẹ; eleyii tí àwon Olorin, Eléré ati akowe ìfẹ fín ta ọjà wọn. Sugbọn, Ọlọrun (nínú ìṣẹ̀dá ati ìwà) ni ife, àyàfi tia ba ri ifẹ gẹgẹbi Irisi Bibeli a' ṣi jina sí ririn nínú ìfẹ.
More
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL