Ifẹ ti o tayọÀpẹrẹ

Ifẹ ti o tayọ

Ọjọ́ 3 nínú 7

Iwa ife 2

Ọkàn ninǔ awọn ewu nlá to onigbagbọ lé ṣubú sí ní riro àrà ẹni ju bi oti ye lọ.Éwu riro àrà ẹni bi ẹnití òpe jẹ ònà sí ìṣubú.

nìgbà ti aba kunna lati wò ará pẹlu irẹlẹ ọkan nínú awojiji Ọrọ Ọlọrun ati ìṣubú awọn ẹlòmíràn, nigbana lo jẹ ẹni tó lè yàrá lati ṣubu sinu idanwo.

Oṣe Ṣe lati de' korita Teniyan yíò ṣi iwawu, kun fún ará rẹ, kun fún igbẹsan, kun fún ikorira débi to ri ará rẹ bi eni to mọ́jú lójú rẹ (Vs. 5) tíó osi korira lati gbo ootọ (Vs. 6)

Nígbà ti eleyii ba di ìwà igba gbogbo, mowi pe ikilọ Nla ni pe oti ya kuro pátápátá kúrò ní ọnà ìfẹ Kristi. Wa nilo ìrẹlẹ ati iṣotitọ ṣí ará rẹ tabi kiõ ni Eni tio máṣe abojuto ìwà rẹ.

Gbin ará rẹ sínú irẹpọ tíó ṣe abojuto ìwà àti ìṣe rẹ. Máṣe dá nikan wá laini ipejopọ awọn ọmọ Ọlọrun.

Siwaju kika: Gal.6:1-3, Rom. 12:3, Hebrew 10:24-25

Adura: OLUWA Rán mi lọwọ, majẹ kin gbọn jù àrà mi lọ.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 2Ọjọ́ 4

Nípa Ìpèsè yìí

Ifẹ ti o tayọ

Ọkàn nínú awọn ọrọ ti an ṣilo julọ ni "Ìfẹ". An tọka sí ní tó fí aimọkan wa hàn. A un fi ìwà inú, ìbálòpọ̀ ati ṣiṣe ifihan ìfẹ dipo rẹ; eleyii tí àwon Olorin, Eléré ati akowe ìfẹ fín ta ọjà wọn. Sugbọn, Ọlọrun (nínú ìṣẹ̀dá ati ìwà) ni ife, àyàfi tia ba ri ifẹ gẹgẹbi Irisi Bibeli a' ṣi jina sí ririn nínú ìfẹ.

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL