Ifẹ ti o tayọÀpẹrẹ
Pataki Lati Dagba Ninu Ifẹ
Igbe Ayé ìfẹ nínú Kristi jẹ ìyí to yẹ kàà ró láti jẹko dàgbà. Ko nṣe ohun taale dédé da lẹsẹ kẹsẹ. Didagba nínú ìfẹ yii ni didagba nínú ìwà Kristi.
Ni pátápátá agbọdọ túnmọ̀ ìfẹ lati inú ìgbé ayé ati ìwà Kristi, Kristi ni kojẹ àpẹrẹ ti an tẹle, ti an wó nínú ìgbàgbọ. Ìhùwà wá sí Ọlọrun ati eniyan yẹ ko dúró lóri ìfẹ.
Àyàfi tíó bá dàgbà nínú ìfẹ, idagbasoke rẹ bi kristeni nbẹ labẹ ipelẹjọ, eleyii jẹ àrídájú pe óòmọ Ọlọrun tíó batilẹ nsọ pe o mọ̀ọ́. Ìfẹ Ọlọrun dì pípé nínú wa tíó tunmọ sí wípé, ohun to ntesiwaju nínú ìdàgbàsókè ni.
Siwaju kika: Hebrew 13:2-3, 1 John 4: 8,12-13
Adura: OLUWA mi Ọwọn b'omi rìn ìfẹ Rẹ nínú òkan mi, latile gbé idagbasoke mi nínú ìfẹ Rẹ rò.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ọkàn nínú awọn ọrọ ti an ṣilo julọ ni "Ìfẹ". An tọka sí ní tó fí aimọkan wa hàn. A un fi ìwà inú, ìbálòpọ̀ ati ṣiṣe ifihan ìfẹ dipo rẹ; eleyii tí àwon Olorin, Eléré ati akowe ìfẹ fín ta ọjà wọn. Sugbọn, Ọlọrun (nínú ìṣẹ̀dá ati ìwà) ni ife, àyàfi tia ba ri ifẹ gẹgẹbi Irisi Bibeli a' ṣi jina sí ririn nínú ìfẹ.
More
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL