Ifẹ ti o tayọÀpẹrẹ

Agbara Ife
Ìfẹ Kristi ni àgbàrá to béè to lè wosan, sọ niji ati dani padà. Ìfẹ yii je ìfẹ tíó ṣoju Ọlọrun ti okan gbogbo eniyan nwa, ti wọn sí nṣe afẹri. Ìwà láàyè àti àgbàrá rẹ koṣe sẹ nigbati àbá ni ìrírí na.
Nígbàtí ìfẹ Ọlọrun yii ba ṣiji bò ọ, yíò mú réré to'n bẹ nínú rẹ jáde ati àwọn ẹlomi tó ba pàdé rẹ, kinidi? Ìfẹ a mã faradà, a mã gba òun gbogbo gbọ, a mā retí òun to dàra nínú elomii. (Vs.7)
Pẹlu ìrù ìfẹ Kristi oṣe ṣe lati faradà òun ti eniyan olè faradà, eleyii ni òun ti Kristi ṣe; Onifẹ rẹ nígbà ti a otọ sí ìfẹ Rẹ, ofi èmi Rẹ le'lẹ ní ìrọ́pò fún wa.
Ẹbùn Ọla nlá ti Ọlọrun na lewa lori ni ifẹ Ọlọrun ti afi pamọ́ sínu Kristi Jésù tó owá nínú awọ eniyan. Gbogbo ẹbun ẹ̀mi míràn nipẹkun ṣugbọn ìfẹ o nipẹkun. (Vs.8)
Siwaju kika: Romans 5:5, 5:6-8, Ephesians 3:17-19
Adura: OLUWA, ran mi lọwọ láti mọ pàtàkì ati lati màà dúpẹ nigbagbogbo fún ẹbun ìfẹ Rẹ.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Ọkàn nínú awọn ọrọ ti an ṣilo julọ ni "Ìfẹ". An tọka sí ní tó fí aimọkan wa hàn. A un fi ìwà inú, ìbálòpọ̀ ati ṣiṣe ifihan ìfẹ dipo rẹ; eleyii tí àwon Olorin, Eléré ati akowe ìfẹ fín ta ọjà wọn. Sugbọn, Ọlọrun (nínú ìṣẹ̀dá ati ìwà) ni ife, àyàfi tia ba ri ifẹ gẹgẹbi Irisi Bibeli a' ṣi jina sí ririn nínú ìfẹ.
More
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL