Ifẹ ti o tayọÀpẹrẹ
Idi ti Ifẹ jẹ Titobi julọ
Láàrin ore ọfẹ nlá mẹta ti a nilo bi onigbagbọ nínú Kristi, bibeli wipe ìfẹ lò tobijulọ. Mo gbagbọ Pe ìfẹ yíò wá titilai, to bẹẹ to jẹ pe ìgbàgbọ́ ati ìrètí sinmi leè ni.
Bíbélì wípé; ìgbàgbọ amáa ṣíṣẹ ninú ìfẹ, ìfẹ ni àmì òdodo igbagbọ wa, kín ṣe ẹsiń.
Bi Àṣe n'reti ipadabọ Kristi tíó lógò, ireti wá nínú ipadabọ jẹ ohun tí ìfẹ wa síi gbèrò, pipa ìfẹ wa mọ ni mímú ireti wá láàyè.
Ìfẹ lò tobijulọ nítori Ọlọrun ni ife. ohun gbogbo to ṣe nipa Ìgbàlà ati ìràpadà wá oṣe wọn nitoriti ìfẹ. Nínú ọrọ idahun Kristi Jésù ofin to gajulọ lati pamọ́ ni ofin ìfẹ; " Fẹràn Olúwa Ọlọrun rẹ pẹlú gbogbo...sí fẹràn ọmọnikeji rẹ gẹgẹbi ará rẹ.
Siwaju kika: Gala. 5:6, John 3:13, James 1:26-27
Adura: Olúwa rán mi lọwọ láti má mú ìfẹ Rẹ wá láàyè nínú mi ni igbagbogbo.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ọkàn nínú awọn ọrọ ti an ṣilo julọ ni "Ìfẹ". An tọka sí ní tó fí aimọkan wa hàn. A un fi ìwà inú, ìbálòpọ̀ ati ṣiṣe ifihan ìfẹ dipo rẹ; eleyii tí àwon Olorin, Eléré ati akowe ìfẹ fín ta ọjà wọn. Sugbọn, Ọlọrun (nínú ìṣẹ̀dá ati ìwà) ni ife, àyàfi tia ba ri ifẹ gẹgẹbi Irisi Bibeli a' ṣi jina sí ririn nínú ìfẹ.
More
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL