Ifẹ ti o tayọÀpẹrẹ
![Ifẹ ti o tayọ](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F49346%2F1280x720.jpg&w=3840&q=75)
Iwa ti ifẹ 1
Oṣe pataki lati ṣe agbe yẹwo ayé rẹ ni ìgbà dé ìgbà bóyá oti kùnà tabi bo ṣinrìn nínú ìfẹ. Itesiwaju rẹ nínú iṣẹgun lórí ẹṣẹ ati ẹran àrà gẹgẹbi onigbagbọ pé fún ipinu lati màà yẹ ìwà ati ibi tò kusi wo.
Ṣíṣe eleyii yíò ràn ẹ́ lọ́wọ́ lati mọ ibì tò kusi ati ìgbésẹ tóyẹ ko gbè, lati ṣe ìdájọ àrà rẹ àti lati ronú piwada. Oṣe ṣe fún ọ lati fọju ṣì awọn àṣìṣe rè nibiti o bati bikita lati ṣe ayẹwo ará rẹ, eleyii jẹ ìgbésẹ ìran rà rẹ lọwọ tí o gbọdọ fi ipinu gbekalẹ.
Lọnà kàn na to ṣekoko lati ṣe ayẹwo ìlera rẹ, oṣe kókó kio ṣe ayẹwo ará rẹ nínú jígí ibi ayẹwo Ọrọ Ọlọrun. Ikuna lati ṣe iyii lẹ jà sí ìṣubú sí kòtò.
Iṣẹ réré rẹ kó léé jẹ àgbàlá odiwọn ìrin rẹ nínú ìfẹ Kristi (Vs.3). Kiyesárà fún àpẹrẹ ìwa aile seun, aile ni sùúrù, ilara, sisọrọ ìgbéraga, ati fifẹ.
Siwaju kika: James 1:23-27, 1 Corinthians 11:31-32
Adura: OLUWA ran mí lọwọ láti ronú piwada ati lati sọ ìfẹ rẹ dọtun nínú ayé mi.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
![Ifẹ ti o tayọ](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F49346%2F1280x720.jpg&w=3840&q=75)
Ọkàn nínú awọn ọrọ ti an ṣilo julọ ni "Ìfẹ". An tọka sí ní tó fí aimọkan wa hàn. A un fi ìwà inú, ìbálòpọ̀ ati ṣiṣe ifihan ìfẹ dipo rẹ; eleyii tí àwon Olorin, Eléré ati akowe ìfẹ fín ta ọjà wọn. Sugbọn, Ọlọrun (nínú ìṣẹ̀dá ati ìwà) ni ife, àyàfi tia ba ri ifẹ gẹgẹbi Irisi Bibeli a' ṣi jina sí ririn nínú ìfẹ.
More
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL