I. Kor 13:9-10

I. Kor 13:9-10 YBCV

Nitori awa mọ̀ li apakan, awa si nsọtẹlẹ li apakan. Ṣugbọn nigbati eyi ti o pé ba de, eyi ti iṣe ti apakan yio dopin.