JÉSÙ ỌBA NÁÀ: Ètò Ìfọkànsìn fún Àjíǹde láti ọwọ́ Timothy KellerÀpẹrẹ
“Ìdánilójú Àìlẹ́tọ̀ọ́sí ”
"Bẹẹni Olúwa", obinrin náà dáhùn pé, “ṣugbọn àwọn ajá a máa jẹ ẹ̀rúnrún oúnjẹ àwọn ọmọ tí ó bá bọ́ sílẹ̀ láti orí tabili." Nígbà náà Jesu dá a lóhùn pé, “Nítorí gbolohun rẹ yìí, máa lọ sí ilé rẹ, ẹ̀mí èṣù náà ti jáde kúrò ninu ọmọ rẹ.” Obìnrin náà bá pada lọ sí ilé rẹ̀, ó rí ọmọde náà tí ó dùbúlẹ̀ lórí ibùsùn, tí ẹ̀mí burúkú náà ti jáde kúrò lára rẹ̀.
(Máàkù 7:28-30)
Ní gbólóhùn míì, obìnrin náà sọpé, "Bẹẹni, Olúwa, ṣùgbọ́n àwọn ọmọ ajá máa ń jẹun lóri tábìlì náà, mọ sì ti wá síbí láti gba tèmi." Jésù bá obìnrin naa sọ̀rọ̀ pẹ̀lú òwe èyí tí ó da ìpènijà àti ànfàní pọ̀, ó sì yee obinrin náà. Ó dáhùn sí ìpènijà náà: "Ó da, ó ti yé mí. Mi ò wá láti Israeli, nkò síi sin Ọlọ́run tí àwọn ọmọ Israeli ńsìn. Nítorí náà, nkò ní ààyè ní orí tábìlì. Mọ fara mo.”
Ṣé èyí kò jẹ́ òun ìyà lénu? Obinrin náà kò fi ṣe ìbínú; kò dúró sí orí ẹ̀tọ́ rẹ. Ó sọ wípé, "Mọ ti gbó, mọ le maa ní ààyè lórí tabili-- ṣùgbọ́n èyí tí ó wà lórí tabili ó pọ̀ tí yóò sí tún kárí gbogbo ènìyàn tí ó wà ní àgbáyé, èmi náà sí fẹ́ gba tèmi nísinsìnyí." Obinrin náà bá Jésù jìjàkadì ní ọ̀nà ìrèlè àti wípé kò ní gba ìdáhùn kòríbẹ́ẹ̀. Mọ ní ìfẹ́ sí ohun tí obinrin náà see.
Ní àṣà tí aláwọ̀ funfun, a kò ní irú ìwà ìdánilójú báyìí. Oun tí a ní ni ìdánilójú sí oun tí ń ṣe ẹ̀tọ́ wa. A kò mọ̀ bí a ṣe le jìjàkaadì àyàfi tí a bá dìde sókè fún ẹ̀tọ́ wa, dúró lóri iyì wa ati ìwà rere wa àti ká ma so wípé "èyí ni gbèsè tí a jẹ mí." Ṣùgbọ́n obìnrin náà kò ṣe bẹ́ẹ̀ rárá. Èyí ni ìdánilójú àìlẹ́tọ̀ọ́sí, ohun tí a kò lè sọ púpọ̀ nípa rẹ̀. Obìnrin náà ko sọ wípé, "Olúwa, fún mi ní oun tí ó tọ́ sí mi gẹ́gẹ́ bi ìwà rere mi" Àmọ́ ó ńsọ wípé "fún mi ní oun tí kò tọ́ sí mi nípa ojú rere rẹ--mo sì nílò rẹ̀ nísinsìnyí" Ṣé ori pé èyí jẹ́ ohun tí ó lapa réré bí obìnrin yìí ṣe mọ̀ tó sì gba ìdojúkọ ati ànfàní tí a fi pamọ́ nínú rẹ̀?
Èsì lọ́nà ìlànà òfin àti ẹ̀kọ́ Júù tí Jésù fún ni pé "ìdáhùn gangan ni eléyìí!" Àwọn ìtumọ̀ míràn ní Jésù wípé "Ìdáhùn tí ó ya ni lénu, ìdáhùn àlárà gbàyídá." Bẹ́ẹ̀ni Jésù dáhùn ẹ̀bẹ̀ rẹ̀ àti wípé a mú ọmọ rè lára dá.
Báwo ni ìgbàgbọ́ arábìnrin kèfèrí yíò ṣe lè nípa lóri ọ̀nà tí ò ń gbà tọ Ọlọ́run wá?
Àyọkà kan láti inú ìwé JESUS THE KING, látọwọ́ Timothy Keller
A tẹ̀ ẹ́ padà ní ìbámu pẹ̀lú àdéhùn pẹ̀lú Riverhead Books, ọmọ ẹgbẹ́ Penguin Group (USA) LLC, A Penguin Random House Company. Àṣẹ ìkọ̀wé © 2011 látọwọ́ Timothy Keller
Àti láti inú ìwé JESUS THE KING STUDY GUIDE látọwọ́ Timothy Keller àti Spence Shelton, Àṣẹ ìtẹ̀jáde (c) 2015 látọ̀dọ̀ Zondervan, ẹ̀ka kan ti HarperCollins Christian Publishers.

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ònkọ̀wé atàwàràwàrà ilé ìtẹ̀wé New York Times tí ó tún jẹ́ oníwàásù Timothy Keller pín àwọn àkàwé àtẹ̀lé ra nípa ayé Jésù bí a ti nínú ìwé Máàkù. Tí a bá wo àwọn ìtàn yí fínnífínní, ó mú ìrína ọ̀tun wá sí ìbáṣepọ̀ tó wà láàrin ayé wa àti ayé ọmọ Ọlọ́run, títí lọ àkókò àjíǹde. JÉSÙ ỌBA NÁÀ ti di ìwé báyìí àti ìlànà ẹ̀kọ́ fún àwọn agbo kéékèèké, ó ńtà kiri ní gbogbo ilé ìtàwé.
More
Àyọkà láti inú àwọn ìwé Riverhead, ọ̀kan nínú àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Penguin Random House, Ìlànà ẹ̀kọ́ láti ọwọ́ HarperCollins Christian Publishers. Fún àlàyé síi, jọ̀wọ́ lọsí: http://www.penguin.com/book/jesus-the-king-by-timothy-keller/9781594486661 or http://www.zondervan.com/jesus-the-king-study-guide